Carolyne Anyango
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Carolyne Anyango Omondi | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Spedag | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Carolyne Anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 27, óṣu february ni ọdun 1989. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Carolyne Kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2016[4].