Cecilia Okoye
No. 7 – B.B.C. Etzella | ||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Position | Iwájú | |||||||||||||
League | N1D | |||||||||||||
Personal information | ||||||||||||||
Born | ọjọ́ kẹtàlá osù kẹsán ọdún 1991 | |||||||||||||
Nationality | American/Nigerian | |||||||||||||
Listed height | 6 ft 1 in (1.85 m) | |||||||||||||
Listed weight | 167 lb (76 kg) | |||||||||||||
Career information | ||||||||||||||
College | McNeese State (2014) | |||||||||||||
NBA draft | 2014 / Undrafted | |||||||||||||
Medals
|
Cecilia Nkemdilim Okoye tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá osù kẹsán ọdún 1991 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-ède Nàìjíríà tí a bí sí orílẹ̀-ède Amerika tí ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti Nàìjíríà fún BBC Etzella àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà . [1]
Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí ní New York sí àwọn òbí tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-ède Nàìjíríà.
Iṣẹ́ òkè-òkun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kópa ní bi 2017 Women's Afrobasket . [2] ó ṣe àròpin ìwọ̀n mẹ́rin, àtúnse méjì ó lé mẹ́rin àti àwọn ìrànlọ́wọ́ ìlàjì fún eré kọ̀ọ̀kan ní àkókò ìdíje fún D’Tigress . Àwọn ẹgbẹ́ náà gba Wúrà ní bi ìfigagbága náà .
Iṣẹ́ orílẹ̀-ède Nàìjíríà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Arábìnrin náà gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti àwọn obìnrin First Bank ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà ti ìlú Èkó tí a mọ̀ sí Elephant Girls nígbà ìdíje 2017 FIBA Africa champions Cup fún ìdíje obìnrin ní Angola. Ìdíje náà wáyé láti ọjọ́ kẹ̀wá di ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù kọkànlá, ní àkókò tí ìdíje àjùmọ̀ṣe ti Ìlú Spanish kò tíí bẹ̀rẹ̀. Ó ṣe àròpin íwọ̀n mẹwa ó lé mẹ́ta, àwọn àtúnṣe máàrún ó lé mẹ́ta àti àwọn ìrànlọ́wọ́ ẹyọ̀kan fún eré kọ̀ọ̀kan ní àkókò ìdíje náà.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ita ìjápọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Cecilia Okoye at FIBA