Jump to content

Celestina Onyeka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Celestina Onyeka
Personal information
Ọjọ́ ìbí15 Oṣù Keje 1984 (1984-07-15) (ọmọ ọdún 40)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2004Pelican Stars
National team
2004Nigeria women's national football team0 (?)(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Celestina Onyeka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu july ni ọdun 1984. Agbabọọlu naa ṣere fun Pelican Stars gẹgẹbi defender[1][2][3].

  • Celestina kopa ninu Olympic to waye ni ọdun 2004 nibi ti o ti jẹ okan lara team awọn obinrin ilẹ naigiria ti apapọ[4].
  1. https://www.worldfootball.net/player_summary/celestina-onyeka/
  2. https://www.olympedia.org/countries/NGR/sports/FBL.1
  3. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=313812
  4. https://www.worldfootball.net/team_performance/nigeria-frauen-team/frauen-olympische-spiele-2004-athen/