Jump to content

Charles Konan Banny

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Charles Konan Banny
Alákóso àgbà orílẹ̀ èdè Côte d'Ivoire kẹfà
In office
7 December 2005 – 7 April 2007
AsíwájúSeydou Diarra
Arọ́pòGuillaume Soro
Governor of the Central Bank of West African States
In office
1990–2005
AsíwájúAlassane Ouattara
Arọ́pòJustin Damo Baro
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1942-11-11)11 Oṣù Kọkànlá 1942
Divo, Ivory Coast, French West Africa, France
Aláìsí10 September 2021(2021-09-10) (ọmọ ọdún 78)
Neuilly-sur-Seine, France
Professioneconomist

Charles Konan Banny (ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1942 – ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù kẹsàn-án ọdún 2021)[1][2][3] jẹ́ olóṣèlú orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire, tí ó jẹ́ Alákóso àgbà orílẹ̀ èdè Côte d'Ivoire láti ọjọ́ keje oṣù Kejìlá ọdún 2005 títí di ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin ọdún 2007.