Charles Olson
Ìrísí
Charles Olson (27 December 1910 – 10 January 1970) je ako-ewi ara Amerika. Ó wà lára àwon tí wón mò mo Black Mountain College. Ònkòwé ni ó sì ti ko òpòlopò ewì kò ní ìfé sí pé à n sàpèjúwe lo re re re nínú ewì tàbí kí a máa lo àfiwé tààrà àlòòdabò.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |