Charles Soludo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Charles Chukwuma Soludo
Gomina Ile Ifowopamo Ijoba ile Naijiria
In office
May 29, 2004 – May 29, 2009
ÀàrẹOlusegun Obasanjo, then Umaru Yar'Adua
AsíwájúJ. O. Sanusi
Arọ́pòS. L. Aminu Sanusi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 July 1960
Aguata LGA, Anambra State
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Nonye
Àwọn ọmọFour
OccupationEconomics Professor

Charles Chukwuma Soludo (ojoibi 28 July, 1960) je ojogbon imo isuna, ohun si ni Gomina ati Alaga igbimo awon oludari Ile Ifowopamo Ijoba ile Naijiria lati 29 May, 2004 titi di 29 May, 2009. Ni ojo kesan osu kokanla odun 2021, Soludo to n soju egbe All Progressives Grande Alliance ni won kede gege bi olubori ninu ibo gomina ipinle Anambra ni odun 2021, ti o si bori awon to sunmo re lati egbe PDP ati APC, Valentine Ozigbo ati Emmanuel Nnamdi Uba.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]