Charly Ndjoume

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Charly Ndjoume (ti a bi ni ọjọ kankanla Oṣu kọkanla ọdun 1986) jẹ oluwe odo Omo orilẹ-ede Kamẹru . O dije ninu ere idaraya 50 mita awọn ọkunrin ni Olimpiiki Igba ooru 2020 . [1]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help)