Cheick Traoré
Cheick Omar Traoré (ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu Kẹta ọdun 1995) jẹ agbabọọlu alamọdaju ti o ngba ibi apa ẹhin -ọtun fun ẹgbẹ Ligue 2 Dijon. Ti a bi ni Faranse, o ṣere fun ẹgbẹ orilẹ-ede Mali.
Igbesi aye ibẹrẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni igba ewe rẹ, Cheick Traoré gba bọọlu pẹlu arakunrin rẹ Baba ni ilu abinibi rẹ Pierrefitte-sur-Seine. Oun na tun jẹ agbabọọlu alamọdaju.
Traoré fowo si iwe adehun nigbati o ti gbooro akọkọ rẹ pẹlu Caen ni ọjọ kerindinlogun Okudu ni ọdun 2015. O lọ si Avranches ni awin, ati lẹhin aṣeyọri Ra npe re, a gbe lọ si Châteauroux. Traoré ṣiṣẹ re pada si Ara mokanla akoko ibẹrẹ ni Châteauroux ati pe o gba gbigbe losi Ligue 1 club Guingamp, won tun gbe lawin pada si Châteauroux fun akoko 2017-18. ifẹsẹwọnsẹ re Akoko nigbat o ti Di ọjọgbọn fun Châteauroux ni ibori 3–2 Ligue 2 pelu Brest ni ọjọ kejidinlogbon Oṣu Keje odun 2017.
Laarin odun 2019 si 2021, Traoré jẹ agbabọọlu fun Lens, ṣe ifarahan meedogun fun ẹgbẹ agbabọọlu naa. Ni ọjọ kejidinlọgbọn osu Okudu ọdun 2021, o fowo si iwe adehun ọdun mẹta pẹlu egbe agbabọọlu Ligue 2 Dijon.
Ise oke'ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ti a bi ni Faranse, Traoré je eniti o wa lati orilẹ-ede Mali. O ṣe afihan fun ẹgbẹ agbaboolu
orilẹ-ede Mali ninu ifẹsẹwọnsẹ 2–1 si South Africa ni ọjketala13 Oṣu Kẹwa Ọdun 2019.
Awọn iṣiro iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Club | Season | League | National Cup | League Cup | Other | Total | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Division | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | ||
Caen II | 2013–14 | CFA 2 | 16 | 0 | — | — | — | 16 | 0 | |||
2014–15 | CFA 2 | 22 | 0 | — | — | — | 22 | 0 | ||||
Total | 38 | 0 | — | — | — | 38 | 0 | |||||
Avranches (loan) | 2015–16 | National | 29 | 0 | 2 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 31 | 0 |
Châteauroux | 2016–17 | National | 26 | 0 | 2 | 0 | 3 | 0 | 0 | 0 | 31 | 0 |
Châteauroux (loan) | 2017–18 | Ligue 2 | 31 | 0 | 3 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | 35 | 0 |
Guingamp | 2018–19 | Ligue 1 | 20 | 0 | 1 | 0 | 5 | 0 | 0 | 0 | 26 | 0 |
Lens | 2019–20 | Ligue 2 | 10 | 0 | 1 | 0 | 2 | 0 | 0 | 0 | 13 | 0 |
2020–21 | Ligue 1 | 2 | 0 | 0 | 0 | — | 0 | 0 | 2 | 0 | ||
Total | 12 | 0 | 1 | 0 | 2 | 0 | 0 | 0 | 15 | 0 | ||
Dijon | 2021–22 | Ligue 2 | 10 | 0 | 0 | 0 | — | 0 | 0 | 0 | 0 | |
Career total | 156 | 0 | 9 | 0 | 11 | 0 | 0 | 0 | 176 | 0 |
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ita ìjápọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- C. Traoré at Soccerway
- Cheick Traoré at National-Football-Teams.com
- Cheick Traoré – French league stats at LFP (archived 2020-01-03) – also available in French (archived 2019-11-08)
- Cheick Traoré – French league stats at Ligue 1 – also available in French
- Cheick Traoré – French league stats at Ligue 2 (in French) – English translation
- Cheick Traoré at SM Caen (in French)
- Cheick Omar Traoré at L'Équipe Football (in French)