Jump to content

Chermoula

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chermoula jẹ́ èròjà oúnjẹ tí wọ́n maá n pèlò ní ilẹ̀ adúláwọ̀, èyí tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá Áfríkà ní àwọn orílẹ̀-èdè bíi Àlgéríà, Líbyà, Mòrókò àti Tùnísíà. Wọ́n maá n lòó láti lékún aadùn oúnjẹ.