Chi-Chi Igbo
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Chi-chi Igbo | ||
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kàrún 1986 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Isiochi, Abia state | ||
Ìga | 1.63m | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2002–2016 | Fortuna Hjørring | 270 | |
National team | |||
2004–2010 | Nigeria | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Chi-Chi Igbo jẹ agbabọọlu orilẹ́ ede naigiria ti a bini 1, óṣu May ni ọdun 1986. Chi-Chi jẹ elere super falcons tẹleri, arabinrin naa ṣere gẹgẹbi ipo forward fun Fortuna Hjørring[1][2][3]
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Agbabọọlu naa kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2007 to waye ni china[4].