Jump to content

Chicago Marathon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chicago Marathon jẹ́ eré-ìje tí wọ́n máa ń sá ni Chicago, Illinois. Ó wà lára àwọn eré-ìje mẹ́fà pàtàkì tí àgbáyé.[1] Bákan náà, ó wà lára àwọn eré-ìje òpópónà tí wọ́n ń díje ní. Eré-ìje Chicago Marathon jẹ́ eré-ìje àgbáyé ẹ̀kẹrin tó tóbi jù lọ ní àgbáyé nípase àwọn tí wọ́n ń sá a parí.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "World Marathon Majors". World Marathon Majors. Archived from the original on February 20, 2009. Retrieved April 22, 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Zumbach, Lauren (October 5, 2016). "On Chicago Marathon weekend, some businesses can't lose". Chicago Tribune. Archived from the original on October 6, 2016. Retrieved October 5, 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)