Chido Onumah
Chido Onumah (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10 oṣù April, ọdún 1966) jẹ́ akọ̀ròyìn, òǹkọ̀wé àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn. Ó ti ṣiṣẹ́ fún bíi ogún ọdún gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn, òǹkọ̀wé, ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn àti oníṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ghana, Canada, India, Orílẹ̀ èdè America, Caribbean àti Europe. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè PhD nínú ẹ̀kọ́ Communication and Journalism láti Autonomous University of Barcelona, ní UAB, orílẹ̀-èdẹ̀ Spain. Ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ètò ààbò ní orílẹ̀-èdẹ̀ Naijiria ni ó mu tí wọ́ sì tí í mọ́lé nígbà tí ó wà ní páápá ọkọ̀ òfurufú ti Abuja, bí ó ṣe ń ti Spain bọ̀ nítorí ó wọ ẹ̀wù tí wọ́n kọ "we are all Biafrans" sí.[1][2][3]
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Onumah kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní University of Calabar, tó wà ní ipinle Cross River, ní orílẹ̀-èdè Naijiria, ó sì gba M.A nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn láti University of Western Ontario, ní London, Ontario, Canada. Ó tún gba PhD kan nínú ẹ̀kọ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti iṣẹ́ ìròyìn[4] láti Autonomous University of Barcelona, UAB, Spain.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Onumah ṣiṣẹ́, ó sì kọ̀wé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà bíi; ìwé-ìròyìn Sentinel, Guardian, AM News, PM News, The News/Tempo, Concord, Punch àti Thisday newspaper, kí oh tó lọ sí Accra, ní orílẹ̀-èdè Ghana, ní ọdún 1996. Ó sìn gẹ́gẹ́ bíi olùṣàtúnṣe alábàáṣiṣẹ́pọ̀ ti ìwé-ìròyìn Insight, olùrànlọ́wọ́ olùṣàtúnṣe ìwé-ìròyìn Third World Network African Agenda, olùṣekòkáárí, West African Human Rights Committee àti correspondent fún ìwé-ìròyìn African Observer, New York, àti AfricaNews Service, Nairobi, Kenya.[5]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 2017: Devatop Anti-Human Trafficking Ambassador, Nigeria.[6]
- 2002: The Jerry Rogers Writing Award, University of Western Ontario, Canada
- 2001: William C. Heine Fellowship for International Media Studies, University of Western Ontario, Canada
- 2001: Alfred W. Hamilton Scholarship - Canadian Association of Black Journalists
- 1999: Kudirat Initiative for Democracy KIND Award for excellence in journalism (Nigeria)
- 1997: Clement Mwale Prize for courage in journalism, AFRICANEWS SERVICE (Kenya)
Ìwé àtẹ̀jáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Onumah jẹ́ òǹkọ̀wé, ó sì ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé bíi:
- "Remaking Nigeria: Sixty Years, Sixty Voices"[7] (ed.)
- "Testimony to Courage: Essays in Honour of Dapo Olorunyomi (with Fred Adetiba)",[8] (ed.)
- "We Are All Biafrans[9][10] (2016),
- Nigeria is Negotiable[11] (2013) àti
- Time to Reclaim Nigeria[12] (Essays 2001-2011) 2011.
O ti satunkọ awọn iwe lori orisirisi wonyen, pẹlu
- Making Your Voice Heard: A Media Toolkit for Children & Youth (2004);
- Anti-Corruption Advocacy Handbook (with Comfort Idika-Ogunye) 2006;
- Youth Media: A Guide to Literacy and Social Change (with Lewis Asubiojo) 2008;
- Understanding Nigeria and the New Imperialism (with Biodun Jeyifo, Bene Madunagu, and Kayode Komolafe) 2006;
- Sentenced in God’s Name: The Untold Story of Nigeria’s "Witch Children" (with Lewis Asubiojo) 2011; àti
- Media and Information Policy and Strategy Guidelines (with Grizzle, A., Moore, P., Dezuanni, M., Asthana, S., Wilson, C. and Banda, F.).[13]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ JournAfrica!. "Chido Onumah". JournAfrica!. Archived from the original on 3 October 2016. Retrieved 30 September 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ International Reporting Project. "Fellows: Chido Onumah". International Reporting Project. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 30 September 2016.
- ↑ Adedigba, Azeezat (29 September 2019). "UPDATED: SSS arrests Nigerian activist Chido Onumah". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/355058-breaking-sss-arrests-nigerian-activist-chido-onumah.html. Retrieved 2 October 2019.
- ↑ "chido onumah bags Phd from university of autonomous". GlobalNoticeHub (Gloablnotice Hin). 23 September 2019. Archived from the original on 23 September 2019. https://web.archive.org/web/20190923201549/https://www.globalnoticehub.com/chido-baggs-phd/. Retrieved 23 September 2019.
- ↑ International Reporting Project. "Fellows: Chido Onumah". International Reporting Project. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 30 September 2016.
- ↑ ICIR, Nigeria (2 March 2017). "Football Star, Popular Actor Among Anti-Human Trafficking Ambassadors". ICIR Nigeria. ICIR Nigeria. https://www.icirnigeria.org/football-star-popular-actor-among-anti-human-trafficking-ambassadors/. Retrieved 29 December 2017.
- ↑ Chido, Onumah (5 December 2020). Remaking Nigeria, Sixty Years, Sixty Voices. ISBN 978-1953967022.
- ↑ Chido, Onumah (27 May 2019). Testimony to Courage: Essays in Honour of Dapo Olorunyomi. ISBN 978-9785443189.
- ↑ "We Are All Biafrans is not about Biafra agitation, says author - OAK TV". oak.tv. Oak TV (Oak TV). Archived from the original on 13 January 2017. https://web.archive.org/web/20170113162809/https://oak.tv/weareallbiafrans-not-biafra-agitation-says-author/. Retrieved 11 January 2017.
- ↑ Onumah, Chido (29 May 2016). We Are All Biafrans (1st ed.). Lagos: Parrésia Publishers Ltd. ISBN 978-9785407983.
- ↑ Onumah, Chido (15 August 2013). Nigeria is Negotiable (1st ed.). Abuja: African Centre for Media & Information Literacy (AFRICMIL). ISBN 978-9789324767.
- ↑ Onumah, Chido (15 December 2011). Time to Reclaim Nigeria. Abuja: AFRICMIL. ISBN 978-9789192403.
- ↑ Amazon. "Chido Onumah". Amazon. Retrieved 30 September 2016.