Jump to content

Chikwendu Kalu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chikwendu Kalu je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tó ń ṣojú ẹ̀ka ìdìbò Ìpínlẹ̀ Gúúsù Isiala Ngwa, ó sì dipò olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Abia ni ìgbìmọ̀ keje. [1] [2]