Jump to content

Chima Nwafor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chima Nwafor (alaisi 25 March, 2005) je oloselu omo ile Naijiria ati igbakeji gomina ipinle Abia si Orji Kalu. O ku ni March 21 2005 won si sin in ni September 2 2006 ni ulu re ni Umuojima ni Ipinle Anambra. Ko pe ti won yo o kuro ni ori oye ti o fi ku. Won se isn idagbere fun un ni St Clement's Anglican Church, Umuojima ni Osisioma Nwa Local Government ni Ipinle Anambra. Alufaa ti o se isn fun un ni Ugochuchwu Ezeoke.