Chinwendu Ihezuo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chinwendu Ihezuo, ti atun mo si Chinwe Ihezuo (ojo-ibi ogbon ojo Osu Kerin 1997) je agbabolu ile Nàìjíríà ti o je atamatase fun BIIK Kazygurt ni ile Kazakisitani ati omo egbe agbabolu obinrin ti ipele ogun ni ile Nijeriya. O ti gba boolu fun Delta Queens ni liigi obinrin Nijeriya. Ni odun 2016, o pari liigi asiwaju obinrin fun UEFA ni 2016-17 pelu BIIK Kazygurt.

Àwọn àkóónú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ibeere Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abi Ihezuo ni ogbon ojo, osu keri odun 1997 ni AjegunleLagos, Nigeria. O lo ibeere aye re ninu palapolo eko. O ga niwon ese bata 5.7. Awon obi re faramo gbigba boolu ni igba ti obere lati mo gba boolu. Iya re faramo gbigba boolu re osi tun ran lowo lati ra awon jesi re ni oja esekuku. Fun gbogbo igba ewe re, o ba awon odomokunrin ni ajegunle lati mo gba boolu papo ni palapolo ajegunle. Adugbo Ajegunle ti pese awon akinkanju ogbontarigi agbabolu okunrin fun Nijeriya. Fun imoriya, ti Ihezuo ba fe se ikeko boolu re, o nife lati keko pelu awon agbaboolu okunrin.

Igba Gbigba Egbe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ihezuo darapo mo kilobu egbe ojobon ti BIIK Kazygurt fun ilu Kazakhstan ni odun 2016 fun odun kan. Ni akoko ibeere re pelu kilobu yii ti o ti wo aso ti oni ami ookandinlogun, o gba boolu erindinlogun wole ni ifarahan ogun. O dije pẹlu awọn egbe re ni odun 2016-17 UEFA ti asaju liigi obinrin, ti o ti bere ere meji. ti osi gba fun 180 iṣẹju lai gba boolu kankan wole ni akoko yii. O si tun gba kaadi ofeefee ni asekagba egbe re pelu Verona leyin ti won ti gboro eta si okan soju Verona. O gba koriya ni liigi asiwaju nigba ti awon egbe re gboro eeta si okan ni ere won pelu Wexford Youths ni idije iyege.

O gba boolu fun Pelican Star ti ilu Calabar lati odun 2012 si odun 2014 leyin ti o tesiwaju si Delta Queens ti osi wa pelu won titi di ipari odun 2015.

International career[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Senior national team[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Following her performance at the 2014 FIFA U-20 World Cup, she was invited to attend a national team training camp for potential selection to the side that would compete at an African Women's Championship in Namibia.

In March 2016, she was one of 40 players called up to prepare for the 2016 Africa Women Cup of Nations. She was a member of the senior national side for the 2015 All African Games in Congo.

U-20 national team[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ihezuo was first called up to the team in 2014. She represented Nigeria at the 2014 FIFA U-20 Women's World Cup where the team narrowly lost in the finals to Germany. She was one of the leading goal scorers in the competition. That year, she also played for the team in a friendly against Ghana. She scored the game's only goal that saw Nigeria win 1–0.

In September 2016, she was invited to the 29 member strong national team training camp that was preparing for the 2018 FIFA U-20 Women's World Cup. She joined the team late for the camp in October in Abuja, after the national team coach threatened her and other overseas players with being dropped if they did not arrive by October 8. She had to miss a training session as she needed time to recover from jet lag. As a player, she acknowledged the pressure she felt at camp going into the tournament to perform well.

She scored seven goals for Nigeria in the qualifying competition for the World Cup. One of her goals came in the 16th minute in their return game against South Africa. The goal qualified Nigeria for the FIFA World Cup. Another goal came in Nigeria's 2–1 victory against Congo DR.

U-17 national team[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ihezuo made her international debut for Nigeria at the 2012 FIFA U-17 Women’s World Cup in Azerbaijan. She came away from the tournament with six goals. Five of these goals came in one game against hosts Azerbaijan, which her team won 11–0. The win was Nigeria's biggest in any FIFA World Cup appearance. Her five goals were also a record for most goals scored in a single game at the FIFA U-17 Women's World Cup. The record has previously been held by Germany’s Kyra Malinowski and South Korea's Yeo Minji, who scored four goals each in the 2010 edition of the tournament. Her fete was matched by Lorena Navarro at the 2016 edition when the Spaniard scored 5 goals against Jordan. Her six goals also earned her the Silver Boot for the tournament. The award was presented to her at the 2012 Annual General Assembly of the Nigerian Football Federation. Her team was eliminated from the tournament after losing to France in the semi-finals.

Not named to the squad in 2013, Ihezuo was also a member of the team in 2014. She again competed at the World Cup, wearing number 19 and playing in the team's game against China where she came on as a substitute.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]