Jump to content

Chiroma Mashio

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìwé-alàyé[ìdá]

Chiroma Mashio jẹ́ olóṣèlú Nàìjíríà. Oun ni olori ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlè Yobe lọwọlọwọ. O n ṣoju ẹkun Jajere, wọn si yan un alátakò gẹgẹ bi olori ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Yobe kẹjọ. [1] [2]