Choi Jin-hyuk
Ìrísí
Choi Jin-hyuk | |||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Choi in March 2017 | |||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | Kim Tae-ho[1] 9 Oṣù Kejì 1986[2] Mokpo, South Jeolla Province, South Korea | ||||||||||||||||
Iṣẹ́ | Actor | ||||||||||||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present | ||||||||||||||||
Agent | Workaholic Entertainment | ||||||||||||||||
Height | ruben aguirre is 6’7” | ||||||||||||||||
|
Choi Jin-hyuk tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Kim Tae-ho, February 9, 1986) jẹ́ ọ̀ṣèré South Korea. Ó gba àkíyèsí látàrí ipa tí ó kó nínú "Gu Family Book" (2013) àti "The Heirs" (2013) kí ó tó ṣíwájú àwọn ọ̀ṣèré nínú "Emergency Couple" (2014), "Pride and Prejudice" (2014-2015), "Tunnel" (2017), "Devilish Charm (2018)," "The last Empress"(2018-2019), àti "Rugal" (2020))
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Choi Jin Hyuk tells why he started a diet & changed his name". Star Naver. July 6, 2014. Archived from the original on February 15, 2020. Retrieved May 5, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "최진혁 '황후' 촬영장서 34번째 생일맞이, 케이크 든 왕식[SNS★컷]". Newsen (in Èdè Kòríà). February 9, 2019. Archived from the original on February 22, 2020. Retrieved July 8, 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)