Jump to content

Chris Abani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chris Abani
Abani in 2007
Ọjọ́ìbíChristopher Abani
27 December 1966 (1966-12-27) (ọmọ ọdún 57)
Afikpo, Ebonyi State, Nigeria
Iṣẹ́Author, poet, professor
Websitechrisabani.com
The poem "Ode to Joy" on a wall in the Dutch city of Leiden

Christopher Abani (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1966) jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Christopher Abani je omo bibi ipinle ebonyi

Ètò-èkó àti Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abani gba ìwé-ẹ̀rí B.A nínú English and Literary Studies ní Fásitì ti ìpínlẹ̀ Imo, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, M.A nínú Gender and Culture ní Birkbeck College, University of London, M.A nínú Imo-ede Geesi ní University of Southern California, àti Ph.D nínú Creative Writing and Literature ní University of Southern California. Abani ti gba àmì ẹ̀yẹ PEN/Barbara Goldsmith Freedom to Write Award, Prince Claus Awards ti ọdún 2001, Lantern Literary Fellowship, California Book Award, Hurston-Wright Legacy Award àti Hemingway Foundation/PEN Award. Díẹ̀ nínú àwọn ewì rẹ̀ jáde nínú jọ́nà kan lórí ẹ̀rọ ayárabíáṣàá Blackbird. Láti ọdún 2007 sí ọdún 2012, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti Creative Writing ní University of California, Riverside. Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Northwestern University.[1] Ìwé ewì rẹ̀ Sanctificum (Copper Canyon Press, ní ọdún 2010), jẹ́ àkójọ ewì tí ó dá lórí ẹbọ ẹ̀sìn, ìfẹ́.[2]

Ààtò àwọn ìwé tí ó ti tẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Novels

Novellas

  • Becoming Abigail (Akashic Books, 2006)
  • Song For Night (Akashic Books, 2007)

Poetry

  • Kalakuta Republic (Saqi, 2001).
  • Daphne's Lot (Red Hen Press, 2003)
  • Dog Woman (Red Hen Press, 2004)
  • Hands Washing Water (Copper Canyon Press, 2006)
  • There are no names for red (Red Hen Press, 2010)
  • Feed me the sun (Peepal Tree Press, 2010)
  • Sanctificum (Copper Canyon Press, 2010)

Essays

  • The Face (Restless Books, 2014)

Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ tí ó gbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

2001

  • PEN USA West Freedom-to-Write Award, US
  • Prince Claus Awards.
  • Middleton Fellowship, University of Southern California, US

2002

  • Imbongi Yesizwe Poetry International Award, South Africa.

2003

  • Lannan Foundation Literary Fellowship, US
  • Hellman/Hammet Grant from Human Rights Watch, US

2005

2006

  • A New York Times Editor's Choice (Becoming Abigail)
  • A Chicago Reader Critic's Choice (Becoming Abigail)
  • A selection of the Essence Magazine Book Club (Becoming Abigail)
  • A selection of the Black Expressions Book Club (Becoming Abigail)
  • Pushcart Nomination (poetry) (A Way To Turn This To Light)
  • Shortlisted for International Dublin Literary Award (GraceLand).

2007

  • The New York Times Editor's Choice (Song for Night)
  • Finalist, PEN/Beyond Margins Award (Becoming Abigail)
  • A Barnes & Noble Discovery Selection (The Virgin of Flames)
  • A New York Times Editor's Choice (The Virgin of Flames)
  • A New York Libraries Books For Teens Selection (Becoming Abigail)

2008

  • Winner, PEN/Beyond Margins Award for Song For Night
  • Nominated for Lamada Award (The Virgin of Flames)
  • Recipient, Distinguished Humanist Award (UC, Riverside)
  • 2007 Pushcart Nomination for Sanctificum (poetry)

2009

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Northwestern Announces Professorships" Archived 28 September 2015 at the Wayback Machine., Northwestern University, 27 June 2013.
  2. Sanctificum. Copper Canyon Press.