Chris Hemsworth

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Chris Hemsworth
Àdàkọ:Post-nominals
Hemsworth at the 2019 San Diego Comic-Con
Ọjọ́ìbíChristopher Hemsworth
11 Oṣù Kẹjọ 1983 (1983-08-11) (ọmọ ọdún 40)
Melbourne, Victoria, Australia
Ẹ̀kọ́Heathmont College
Iṣẹ́
  • Actor
  • producer
Ìgbà iṣẹ́2002–present
Olólùfẹ́
Elsa Pataky (m. 2010)
Àwọn ọmọ3
Àwọn olùbátan
Signature

Christopher Hemsworth AM (ti a bi 11 August 1983 [1] ) jẹ oṣere ilu Australia. Ó di gbajugbaja ati olokiki látara sise ẹ̀dá itan Kim Hyde ninu ere agbeleewo tẹlifiṣọn orile ede Australia Home and away (2004 – 2007) ṣaaju ki o to bẹrẹ iṣẹ fiimu ni Hollywood . Ninu Agbaye Cinematic Marvel (MCU), Hemsworth bẹrẹ ṣise ẹ̀dá itanThor pẹlu fiimu 2011 ti oni orukọ kanna pelu ẹ̀da itan nàa ati atunṣe ẹ̀da itan naa ninu ere ti o se n ko pẹ́ ko pẹ́ yii ninu ere Thor: Love and Thunder (2022), eyiti o fi idi rẹ mulẹ laarin awọn oṣere ti o sanwo julọ ni agbaye.

  1. . Archived on 19 May 2018. Error: If you specify |archivedate=, you must first specify |url=.