Christopher Gwabin Musa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀gágun Major General Christopher Gwabin Musa (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1967)[1] jẹ́ Ọ̀gágun-àgbà tí ó ga jùlọ fún ààbò orílẹ̀-èdè Nigeria, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kàdúná sùgbọ́n tí wọ́n bí sí Sokoto. Ààrẹ Bọlá Ahmed Tinubu ni ó yàn án gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gágun-àgbà tí ó ga jùlọ fún ààbò orílẹ̀-èdè Nigeria lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 2023 lẹ́yìn tí Ààrẹ pàṣẹ láti yọ àwọn Ọ̀gágun àgbà tí wọ́n ga jùlọ lẹ́nu iṣẹ́.[2][3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Anichukwueze, Donatus (2023-06-19). "PROFILE: Meet New Chief of Defence Staff, Christopher Musa". Channels Television. Retrieved 2023-06-20. 
  2. Bankole, Idowu (2023-06-20). "Tinubu sacks service chiefs, dissolves boards of MDAs". Vanguard News. Retrieved 2023-06-20. 
  3. Reporters, Our (2023-06-20). "Tinubu removes security chiefs, Customs boss, appoints Ribadu, Egbetokun, others". Punch Newspapers. Retrieved 2023-06-20. 
  4. "Tinubu appoints Service Chiefs, CDS, NSA, IG, CGC". The Nation Newspaper. 2023-06-20. Retrieved 2023-06-20.