Christopher Okojie
Christopher G Okojie OFR DSc (1920-2006) jẹ́ dókítà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olóṣèlú, olùdarí àti ònímọ̀-ìtàn. A bíi ní Ugboha, ní ìpínlẹ̀ Ẹdó, orílè èdè Nàìjíríà. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ olùdarí ilé ìgbìmò àṣòfin àrin-gùn-gùn ìwọ̀ oòrùn láàárín ọdún 1964-1966. Ó ti fìgbà kan jẹ́ mínísítà fún ẹ̀ka ìlera fún ìjọba àpapọ̀ Olómìnira tí ilé Nàìjíríà (1992) àti Ààrẹ fún àjò- tí - o-rí - sí- ọ̀rọ̀ - ìlera ní orílè - èdè Nàìjíríà (1974-1975). Gẹ́gẹ́ bí mínísítà, ó jẹ́ irinṣẹ́ nínú ìtẹ̀síwájú ẹ̀ka ìjọba àpapọ̀ tí ó rí sí ìdójútòfò ìlera.[1] Ó kú ní ọjọ́ kéje, oṣù kẹwàá ọdún 2006, ní ọmọ ọdún ìkẹrindínláàdọ́rùn-ún, ní ìgbà ti rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i mínísítà, ó ní ànfàní àti ṣe ọ̀nà àti omi ẹ̀rọ fún àwọn ènìyàn Esan.
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga àgbà tí ìmò ìsègùn òyìnbó àpapọ̀ (2002), ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé ẹ̀kọ́- ìmò- iṣẹ́- abẹ - tí-àgbáyé àti ọmọ-ẹgbẹ́ ìgbìmò -òǹkà-iye- ènìyàn- tí New York.[2] Ní ọdún-un 1964, láti fi mọrírì ìṣè-jọba rẹ̀ sí orílẹ̀ èdè, Okojie ní a fi àmì ẹ̀yẹ (National honour of officer of the Order of the Federal Republic(OFR).[3]
Iṣẹ́ tí ó yàn láàyò.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dókítà Christopher Gbelokoto Okojie fi isẹ́ ìjọba sílẹ̀ láti ṣiṣẹ́ láàárín àwọn ènìyàn rẹ̀,àwọn mẹ̀kúnnù ara Ishan (Esan) ní Ìpínlẹ̀ Edo.[4] Ó padà lọ sí ẹ̀kun ìdìbò rẹ̀, ó sì ṣe ìdásílẹ̀ ilé-ìwòsàn Zuma Memorial Hospital ní March 27, 1950. Láti ṣiṣẹ́ ní ilé-ìwòsàn, Okojie lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún láti ṣe ìwádìí nípa ìtàn Esan, òfin àti ìṣe. In 1960, he published a most comprehensive study on Esan history, Esan Native Laws and Customs: With Ethnological Studies of the Esan People. He had a long and illustrious career and continued to attend to patients when aged 85.[5]
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]He married Olayemi Phillips, and they had seven children. Their children include daughters: Oseyi Oigboke, Anehita Akinsanya, Adesua Ilegbodu and Ebemeata Ani-Otoibhi and sons: Isi Okojie, and twins Ihimire Okojie and Ehidiamen Okojie (who died in December 2009). He owned and lived in a large estate, Zuma Memorial, in Irrua Edo State which comprised his personal residence, a hospital (Zuma Memorial Hospital), orphanage and accommodation for medical and domestic staff.[citation needed]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Health Insurance Scheme Takes Off Soon", The Daily Trust. October 9, 2001
- ↑ "Dr Christopher G. Okojie". 30 June 2018.
- ↑ "OKOJIE, Dr. Christopher Gbelokoto". 1 July 2018.
- ↑ "THE ESAN(NIGERIA)PEOPLE: FORTY-FIVE YEARS AFTER C.G.OKOJIE’S ISHAN NATIVE LAWS AND CUSTOMS". 30 June 2018. Archived from the original on 30 June 2018. Retrieved 10 November 2023.
- ↑ Okonofua, Friday (2006). "In Memoriam: Dr Christopher Gbelokoto Okojie". Journal of Medicine and Biomedical Research 5 (2). http://www.bioline.org.br/pdf?jm06012.