Jump to content

Chukwuemeka Emmanuel Nwogbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chukwuemeka Emmanuel Nwogbo je oloselu omo orilẹ-ede Nàìjíríà to ṣiṣẹ gẹgẹbi bi ọmọ ile ìgbìmọ̀ asoju ṣòfin Naijiria to n sójú àgbègbè Awka North/Awka South ti Ipinle Anambra ni Apejọ orile-ede Naijiria keje lati 2011 si 2015. O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti All Progressive Grand Alliance (APGA). [1] Ni 2013, Nwogbo kopa ninu APGA primaries fun ipo gomina Anambra ṣugbọn o padanu si Willie Obiano, ẹniti o di oludije ẹgbẹ naa.