Cinithian
Ìrísí
Cinithians' jẹ́ àwọn ẹ̀yà Berber ní Àríwá Áfríkà,[1] tí wọ́n gbé níbi tí Algeria wà ní òde òní.[2]
Ọ̀pọ̀lopọ̀ àwòrán àti àkọ́lẹ̀ ni ó jẹri sì pé wọ́n gbé ní ibẹ̀. Ní ẹgbẹ́ Githis, ní gúúsù Tunisia, wọ́n ṣe ère láti yẹ́ ìjọba Roman àti Memmius Pacatus sí. Àwọn onítàn gbàgbọ́ pé Memmius ni adarí ẹ̀yà Cinithians, òun sì ni ẹni àkọ́kọ́ nínú ìdílé rẹ̀ láti di Sẹ́nátọ̀.
Ní ègbẹ́ ìletò àwọn Sitifis, àkọlẹ̀ míràn tún wà nípa àwọn ẹ̀yà Cinithians.[3]
Onítàn Cornelius Tacitus tún sọ nípa wọn pé wọ́n jẹ́ "...orílẹ̀ èdè tí kò ní ẹ̀gàn rárá".[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jean Baptiste Louis Crevier, The History of the Roman Emperors: From Augustus to Constantine, Volume 10 (F. C. & J. Rivington, 1814 ) p220.
- ↑ Cornelius Tacitus, The Annals and History of Tacitus (Talboys, 1839)p75.
- ↑ The Berbers, page 31.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Cornelius Tacitus, The Annals and History of Tacitus (Talboys, 1839) p113.