Citrus australasica

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Citrus; please create it automated assistant
Australian finger lime
Green skin type finger lime
Green skin type finger lime
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Template:Taxonomy/CitrusC. australasica
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/CitrusCitrus australasica
Synonyms[1]

Citrus australasica, èyí tó jẹ́ láìmù tó farajọ ìka ti ilẹ̀ Austraila tàbí caviar lime, jẹ́ igi kékeré ẹlẹ́gùn-ún tó máa ń wà ní ilẹ̀ olómi tàbí ní irà ní agbègbèQueensland àti New South Wales, Australia.

Ó ní èso tó ṣe é jẹ, èyí tí wọ́n sì máa ń tà lóríṣiríṣi.[2][3]

Bí ó ti rí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Igi náà ní 2–7 m (6 ft 7 in–23 ft 0 in) ní gíga. Àwọn ewé rẹ̀ kéré bí i 1–6 cm (0.39–2.36 in) wọ́n sì gùn tó 3–25 mm (0.12–0.98 in) ó fẹ̀, pẹ̀lú ẹnu tó rí ṣonṣo. Òdòdó rẹ̀ funfun, ó sì tó 6–9 mm (0.24–0.35 in) ní gígùn. Èso náà rí kuduru, ó sì tó 4–8 cm (1.6–3.1 in) ní gígùn. Nígbà mìíràn, ó máa ń lọ́, tó sì máa ń ní oríṣiríṣi àwọ̀, bí i píǹkì àti aláwọ̀ ewé.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Citrus australasica F.Muell. — The Plant List". www.theplantlist.org. Archived from the original on 2018-12-26. Retrieved 2014-04-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Citrus pages, Native Australian Citrus, Citrus australasica". users.kymp.net. Archived from the original on 2021-12-22. Retrieved 2014-04-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Mueller, Ferdinand von (April 2, 1858). Fragmenta phytographiæ Australiæ /. v.1 1858-59. Auctoritate Gubern. Coloniæ Victoriæ, Ex Officina Joannis Ferres. https://www.biodiversitylibrary.org/item/7218. Retrieved April 2, 2020. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named heidiwest2