Claude Haffner
Ìrísí
Claude Haffner | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | كلود هافنر |
Ọjọ́ìbí | 1976 (ọmọ ọdún 47–48) Kinshasa, Congo Republic |
Orílẹ̀-èdè | |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | Director, production manager, screen writer, actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2000–present |
Parents |
|
Àwọn olùbátan | Frédéric Haffner (brother) |
Claude Haffner (tí wọ́n bí ní ọdún 1976) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Fráǹsì àti Kóngò. Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tó fi mọ́ Ko Bongisa Mutu, Défilé Célianthe àti Noire ici, blanche là-bas.