Coke
Appearance
Type | Soft drink (Cola) |
---|---|
Manufacturer | The Coca-Cola Company |
Country of origin | United States |
Introduced | 1886 |
Color | Caramel E-150d |
Flavor | Cola, Cola Green Tea, Cola Lemon, Cola Lemon Lime, Cola Lime, Cola Orange and Cola Raspberry. |
Variants | See Brand portfolio section below |
Related products | Pepsi Irn Bru RC Cola Cola Turka Zam Zam Cola Mecca Cola Virgin Cola Parsi Cola Qibla Cola Evoca Cola Corsica Cola Breizh Cola Afri Cola |
Coke tí a tún máa ń pè ní Coca-Cola jẹ́ nǹkan mímu ẹlẹ́rìndòdò tí tí ó wà káàkiri ọ̀pọ̀ orílẹ̀ èdè, tí wọ́n fi ń pòhùngbẹ tí ilé-iṣẹ́ Coca-Cola Bottling Company ń ṣe lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ John Stith Pemberton ni ó ṣẹ̀dá Coke ní sẹ̀ńtúrì ọkàn dínlógún (19th Century), tí ó sìn tà á fún oníṣòwò kan nígbà náà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Asa Griggs Candler, tí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí atajà jẹ́ kí Coke gbajúmọ̀ káàkiri gbogbo àgbáyé.[1] [2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The Coca-Cola Company - History, Products, & Facts". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-01-03.
- ↑ "Coca-Cola History │ World of Coca-Cola". World of Coca-Cola. Archived from the original on 2018-05-02. Retrieved 2020-01-03.
- ↑ "Coca-Cola History". The Coca-Cola Company. 2013-01-01. Retrieved 2020-01-03.