Jump to content

John Stith Pemberton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the American druggist. Fún other people named John Pemberton, ẹ wo: John Pemberton (disambiguation).
John Stith Pemberton
Ọjọ́ìbí(1831-07-08)Oṣù Keje 8, 1831
Knoxville, Georgia, United States
AláìsíAugust 16, 1888(1888-08-16) (ọmọ ọdún 57)
Atlanta, Georgia, United States
Resting placeOld City Cemetery (Columbus, Georgia)
IbùgbéPemberton House
Ẹ̀kọ́Reform Medical College of Georgia
Iṣẹ́Biochemist
Gbajúmọ̀ fúnInventor of Coca-Cola
Olólùfẹ́Ann Eliza Clifford Lewis
Àwọn ọmọ1
John Stith Pemberton
Allegiance Confederate States of America
Service/branch Adigun Confederate States of America
Years of service1861–65 (Confederate States Army)
Rank Lieutenant Colonel
UnitThird Cavalry Battalion of the Georgia State Guard
Battles/warsAmerican Civil War

John Stith Pemberton tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1831 (July 8, 1831) tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ 1888 (August 16, 1888) jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì biochemist àti oluṣẹ̀dá ohun mímu ẹlẹ́rìndọ̀dọ̀, Cola-cola ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó tún jẹ́ ajagunfẹ̀yìntì tí ó jagun abẹ́lé tí orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Lọ́dún 1886 ló ṣẹ̀dá Coca-Cola tí ó sìn ta ẹ̀tọ́ ìṣẹ̀dá rẹ̀ fún ilé iṣẹ́ Coca-Cola Company kí ó tó kú. [1] [2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "John S. Pemberton". Lemelson-MIT Program. Archived from the original on 2020-01-03. Retrieved 2020-01-03. 
  2. Griffenhagen, G.B.; Stieb, E.W.; Fisher, B.D. (1999). A Guide to Pharmacy Museums and Historical Collections in the United States and Canada. New Series. American Institute of the History of Pharmacy. p. 23. ISBN 978-0-931292-34-7. https://books.google.com/books?id=O1KpXC4dDSkC&pg=PA23. Retrieved 2020-01-03. 
  3. "NPGallery Asset Detail". NPGallery Search. Retrieved 2020-01-03.