Cole urceolata

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Cola; please create it automated assistant
Àdàkọ:Speciesbox/hybrid name
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/ColaCola urceolata
K.Schum. (1900)
Synonyms

Cola urceolata, ti a tun mo sí bemange, bokosa, eboli, egwasa, ikaie, lekukumu, lungandu, lusakani, matadohohu, nesunguna, ngbilimo, ngono, ati zimonziele, je alododo shrubu ni idile Malvaceae.[1] Specific epithet (urceolata) wa lati Latin urceus (= pitcher, jug) ati wipe o tun mo sí "urn-shaped".

Wiwa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cola urceolata je ara orile-ede Central Africa, lati southeastern Naijiria south to Kongo Central province si Democratic Republic of the Kongo ati northeast sí southeastern Central African Republic.[2]

Àpèjúwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cola urceolata je evergreen shrubu ti didagba re to 3 meters (9.8 feet) ni giga.[1] Awo ewe re dudu ,o sì rí roboto,ododo re je ofeefe sí funfun,petali re je meta.[2] Eso re jọ irisi ata,o sì maan pupa ti o ba pon,a sì máa ni awo ewe ti ko ba pon. O curvu ati taper pointi sí nonstem end. Won ma nsaba dagba ni clusteri,won saba maan je meta. Eso yìí,irúgbìn,ododo ati ewe re je jije.[1]

Lilọ re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Eso yìí ati awọn ara irúgbìn se je tabi ki won se ni ona awon baba wa.[1]

Tun wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn Atokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Cola urceolata". Let's Plant. Archived from the original on 14 December 2023. Retrieved 1 March 2021. 
  2. 2.0 2.1 "Cola urceolata K.Schum.". www.gbif.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 1 March 2021.