Colin Howell

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Colin Howell (bi Ọjọ́ Kẹrìnlá Oṣù Kẹta Ọdún 1959) jẹ́ Northern Irish tí a gbé si ẹ̀wọ̀n fún ẹ́sún apànìyàn. Àwon Apànìyàn áti ìròyìn tì o yíi wọn ká jẹ́ fífi hàn lóri ITV eré onípele "The Secret" gbóhùnsáféfé ní Oṣù Kẹrin àti Oṣù Karun Ọdún 2016.

Howell pa aya rẹ̀ Lesley (née Clarke) àti Olólùfé Ọkọ rẹ́, Trevor Buchanan (tí ó jẹ osísẹ́ RUC ), ní òhun tí o fí hàn bí ìlànà ìpara-eni láàrín olólùfé méjì. Àwon Ara-ẹ̀dá wọ̀nyí nì a ri nínù ọkọ̀ elè-èfín ni Castlerock ní 19 Oṣù Karun 1991.[1]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]