Cordelia Agbebaku
Ìrísí
Prof. Cordelia Agbebaku | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oṣù kínní ọdún 1961 Ekpoma |
Aláìsí | Ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kejì ọdún 2017 Benin |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Olólùfẹ́ | Phillip Agbebaku |
Cordelia Ainenehi Agbebaku (tí a bí ní oṣù kínní ọdún 1961) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti adarí Yunifásítì Ambrose Alli télèrí.
Ìtàn ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Agbebaku ní ìlú Ekpoma ní oṣù kínní ọdún 1961. Ó kó nípa ìmọ̀ òfin ní Yunifásitì Bendel tí a mọ̀ sí Yunifásitì Ambrose Alli lọ́wọ́ lọ́wọ́.[1] Agbebaku di adarí Yunifásítì Ambrose Alli (AAU) ní ọdún 2014 nígbà tí Gómínà Adams Oshiomhole yán sípò náà.[2][1] Agbebaku fi sílè ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kejì ọdún 2017, ní Ilé ìwòsàn Yunifásitì Benin, ó sì fi ọkọ rẹ̀ - Ọ̀jọ̀gbọ́n Phillip Agbebaku àti àwọn ọmọ rẹ̀ sáyé.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "History of Ambrose Alli University, Ekpoma". Archived from the original on 3 February 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Appointment of a Substantive Vice-Chancellor For Ambrose Alli University, Ekpoma". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Okere, Alexander. "Ex- AAU VC,Prof. Agbebaku, dies at 55". Punchng.