Cornelius Nnaji
Ìrísí
Cornelius Prince Nnaji jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti onsójú Enugu East/Isi-Uzo ni Ile Awọn Aṣoju ṣòfin àgbà.
Igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ iṣelu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdun 1973 ni wọn bi Cornelius Nnaji, o si wa lati ìpínlè Enugu . Ni ọdun 2019, o rọpo Kingsley Ebenyi lati dibo si ile igbimọ aṣofin apapọ labẹ ẹgbẹ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). [1] [2]
Àwọn ẹjọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nnaji tún dije ni inú oṣù keji ọdún 2023 nfun ìgbà keji ṣùgbọ́n alátakò re ojogbon Sunday Nnamchi ni won kéde gẹgẹbi ebi eniti o jawe olubori lati inú ẹgbẹ òṣèlú Labour Party. Ijawe olubori yii ni Nnaji pe ẹjọ le lori ni ile ẹjọ ko tèmi lọrun ṣùgbọ́n ile ẹjọ fagile ejo re pẹlu ẹsun wípé ko ni ohun amuye ti o le fi dije dun ipo náà [3][4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Empty citation (help)"Legislator Details - ConsTrack Track and Report on Governement Funded Projects in Nigeria". constrack.ng. Retrieved 2025-01-03.
- ↑ Empty citation (help)"Citizen Science Nigeria". citizensciencenigeria.org. Retrieved 2025-01-03.
- ↑ https://punchng.com/tribunal-sacks-enugu-rep-declares-pdp-candidate-winner/?amp
- ↑ https://dailypost.ng/2023/11/03/reps-seat-appeal-court-sacks-cornelius-nnaji-upholds-election-of-lps-nnamchi/