Jump to content

Cosmos Ndukwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Cosmos Ndukwe je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O je igbákejì olórí ilé ìgbìmò aṣòfin to n sójú àgbègbè Bende South ni ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlẹ̀ Abia . [1] Ni ọdun 2023, o darapọ mọ ìdíje aarẹ labẹ ẹgbẹ òṣèlú ti Peoples Democratic Party (PDP). [2] [3]