Jump to content

Crawford University

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Crawford University
MottoKnowledge with Godliness
Established2005
TypePrivate University
Parent institutionThe Apostolic Faith Mission
ChancellorRev. Emmanuel Adebayo Adeniran
Vice-ChancellorProf Isaac Rotimi Ajayi
Pro-ChancellorProfessor Peter Okebukola
Academic staffCollege of Natural and Applied Sciences, College of Business and Social Sciences, College of Agriculture.
LocationIgbesa, Ogun State, Nigeria
CampusFaith City, Igbesa Ogun State, NIGERIA.
Websitehttp://www.crawforduniversity.edu.ng

Ile-ẹkọ giga Crawford jẹ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládáni ti Kristẹ́nì Apostolic Faiyh Mission. kan tí ó wà ní ilú Ìgbẹsà, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní Nigeria .[1]

Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọdún 2005, nípa sẹ̀ ọ̀gbẹ́ni Paul Akazue, tí ó jẹ́ adarí àti igbá kẹta nínú iṣẹ́ ìgbàgbọ́ ti Apostolic jákè ja do ilẹ̀ Adúláwọ̀ nígbà náà. Olùṣọ́ Paul Akazue ni Olùdásílẹ̀ àti Alákòóso pátá pátá akọ́kọ́ fún ilé-ẹ̀kọ́ náà ṣáájú kí ó to papò dà ní oṣù Karùún ọdún 2010. [2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Official List of Courses Offered in Crawford University (CRAWFORD)". Myschool. Retrieved 2019-12-16. 
  2. "Crawford University – Knowledge with Godliness". Crawford University – Knowledge with Godliness. Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-16. 
  3. "Crawford holds 10th convocation, graduates 27 first class students - Nigeria and World NewsFeatures - The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News. Retrieved 2019-12-16. 

Àwọn ìtàkùn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]