Cristiano Ronaldo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Cristiano Ronaldo
Personal information
OrúkọCristiano Ronaldo dos Santos Aveiro[1]
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kejì 1985 (1985-02-05) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíFunchal, Madeira, Portugal
Ìga1.87 m[note 1]
Playing positionForward
Club information
Current clubJuventus
Number7
Youth career
1992–1995Andorinha
1995–1997Nacional
1997–2002Sporting CP
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2002–2003Sporting CP B2(0)
2002–2003Sporting CP25(3)
2003–2009Manchester United196(84)
2009–2018Real Madrid292(311)
2018–Juventus48(37)
National team
2001Portugal U159(7)
2001–2002Portugal U177(5)
2003Portugal U205(1)
2002–2003Portugal U2110(3)
2004Portugal U233(2)
2003–Portugal164(99)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19 January 2020.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 14 November 2019
Christiano Ronaldo

Ìtàn nípa rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cristiano Ronaldo tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Cristiano Ronaldo dos Santos Aveiro tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1985 (5th February 1985) jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́kà agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀ èdè Potugi, tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá Manchester United lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì (England). Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí wọ́n mọ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jùlọ ni àgbáyé. Ẹ̀marùn-ún ni ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ Ballons d'Or ẹni tí ó mọ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá gbá jùlọ ni àgbáyé. Bẹ́ẹ̀ náà, ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ ẹni tí ó gba bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá sáwọn jù ni ẹ̀mẹẹ̀rin, ó sìn gba ife ẹ̀yẹ ókàndínlọ́gnọ̀n pẹ̀lú onírúurú ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ni orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, Spain, Àti Italy.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "FIFA Club World Cup UAE 2017: List of players: Real Madrid CF" (PDF). FIFA. 16 December 2017. p. 5. Archived from the original (PDF) on 23 December 2017. Retrieved 23 December 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Naakka, Anna-Maija (25 July 2015). "Mitä Ronaldo touhuaa, eikö pituus riitä?". yle.fi (in Finnish). Yleisradio. Retrieved 22 July 2019. 
  3. "Portugals EM-trupp". SvD.se (in Swedish). 22 May 2008. Retrieved 24 July 2019. 
  4. Kay, Stanley (16 August 2017). "How Tall is Cristiano Ronaldo?". Sports Illustrated. Retrieved 13 July 2019. 
  5. Caioli 2016.
  6. Lundell, Johan (23 May 2010). "Älskad eller hatad – Cristiano Ronaldo" (in Swedish). Sveriges Television. Retrieved 24 July 2019. 
  7. "2018 FIFA World Cup Russia™ - Players - CRISTIANO RONALDO". FIFA.com. Fédération Internationale de Football Association (FIFA). 16 August 2017. Retrieved 13 July 2019. 
  8. "Cristiano Ronaldo | EA SPORTS FUT Database | FIFA Ultimate Team". Official website of EA Sports. Retrieved 24 July 2019. 
  9. "Cristiano Ronaldo" (in Èdè Pọtogí). Portuguese Football Federation (FPF). Retrieved 22 July 2019. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found