Jump to content

50 Cent

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Curtis Jackson)
50 Cent
50 Cent at the 2009 American Music Awards
50 Cent at the 2009 American Music Awards
Background information
Orúkọ àbísọCurtis James Jackson III
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Keje 1975 (1975-07-06) (ọmọ ọdún 49)[1]
Ìbẹ̀rẹ̀South Jamaica, Queens, New York, I.A.A.
Irú orinHip hop
Occupation(s)Rapper
Years active1997–present
LabelsShady, Aftermath, Interscope
Associated actsG-Unit, Dr. Dre, Eminem, Sha Money XL
Website50cent.com

Curtis James Jackson III (ọjọ́ ìbí Oṣù Kéje 6, 1975), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ 50 Cent, jẹ́ ará Amẹ́ríkà olórin tàkásufé, olùtajà, olùdókòòwò, atọ́kùn àwo orin, àti òsèré. Ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí àwọn àwo rẹ̀ "Get Rich or Die Tryin'" (2003) ati "The Massacre" (2005) jade. "Get Rich or Die Tryin'" ti gba ìwé-ẹ̀rí platinum mẹ́jọ láti ọwọ́ RIAA.[2] Àwo rẹ̀ "The Massacre" gba ìwé-ẹ̀rí platinum máàrún láàtı ọwọ́ RIAA.[2]

Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wón bí Jackson ní Queens, ìlú New York, tí Sabrina tí se ìyá rẹ tọ dàgbà ni Jamaika.[3]

Ó bẹ̀rẹ̀ sí n ja ijaelese ni ọmọ ọdún mọ́kànlá. Ní ọmọ ọdún méjìlá, ó bẹ̀rẹ̀ si nta ògùn olóró nígbà tí awọn òbí òbí rẹ ro wípé o wa ní ilé ẹ̀kọ́.

Àkójọ awọn ẹ̀bùn àmì ẹyẹ atí àyẹ́sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

American Music Awards

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

50 Cent gbà ẹbùn àmì ẹyẹ méta nínu mefa ti wọn ti pe ni American Music Awards ọlọ́dọdún.[4][5]

Ọdún Àkọ́ọ́lé Ẹ̀bùn Èsì
2003 Get Rich or Die Tryin' Favorite Rap/Hip-Hop Album Gbàá
50 Cent Favorite Rap/Hip-Hop Male Artist Gbàá
Fan's Choice Award Wọ́n pèé
2005 The Massacre Favorite Rap/Hip-Hop Album Gbàá
50 Cent Favorite Pop/Rock Male Artist Wọ́n pèé
Favorite Rap/Hip-Hop Male Artist Wọ́n pèé

Rhythm & Soul Music Awards

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àkọ́ọ́lé Ẹ̀bùn Èsì
2004 50 Cent Songwriter of the Year3 Gbàá
"In da Club" Top R&B/Hip-Hop Song Gbàá
"In da Club" Top Rap Song Gbàá
2005 "In da Club" Top Ringtone Song of the Year Gbàá
2006 50 Cent Songwriter of the Year4 Gbàá
"How We Do" Top Rap Song Gbàá
"Candy Shop" Ringtone of the Year Gbàá
Ọdún Àkọ́ọ́lé Ẹ̀bùn Èsì
2003 50 Cent Best New Artist Gbàá
Best Male Hip-Hop Artist Gbàá
2004 50 Cent Best Male Hip-Hop Artist Wọ́n pèé
G-Unit Best Group Gbàá
"Hate It or Love It" Best Collaboration Wọ́n pèé
2005 50 Cent Best Male Hip-Hop Artist Wọ́n pèé
2006 50 Cent Best Hip-Hop Artist Wọ́n pèé
Best Male Hip-Hop Artist Wọ́n pèé
Ọdún Àkọ́ọ́lé Ẹ̀bùn Èsì
2007 50 Cent Hustler of the Year Gbàá
"I Get Money" Track of the Year Wọ́n pèé
Best Hip Hop Video Wọ́n pèé
2008 50 Cent Hustler of the Year Wọ́n pèé
2009 Thisis50 Best Hip Hop Online Site Wọ́n pèé
2010 Thisis50 Best Hip Hop Online Site Wọ́n pèé



Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "How old is 50 Cent?". Capital XTRA. November 1, 2018. Archived from the original on November 18, 2022. Retrieved November 18, 2022. 
  2. 2.0 2.1 "50 Cent Film Offers New Version of Rapper – Celebrity Gossip | Entertainment News | Arts And Entertainment". Fox News. November 7, 2005. http://www.foxnews.com/story/0,2933,174864,00.html. Retrieved May 12, 2010. 
  3. Hattenstone, Simon (May 4, 2020). "50 Cent on love, cash and bankruptcy: ‘When there are setbacks, there will be get-backs’". the Guardian. Retrieved November 18, 2022. 
  4. 31st American Music Awards Archived November 22, 2016, at the Wayback Machine.. Rock on the Net. Accessed on June 16, 2007.
  5. 33rd American Music Awards Archived November 22, 2016, at the Wayback Machine.. Rock on the Net. Accessed on June 16, 2007.