Cynthia Uwak

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Cynthia Uwak
Personal information
OrúkọCynthia Uwak
Ọjọ́ ìbí15 Oṣù Keje 1986 (1986-07-15) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.6m
Playing positionForward (association football)#Striker
Club information
Current clubÅland United
Number18
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2005Kuopion MimmiFutis
2006FC United (Finland)(17)
2007Falköpings KIK
2008FC United (Finland)
2008–2009Olympique Lyonnais (ladies)
2009Kuopion MimmiFutis12(18)
2009–20111. FC Saarbrücken42(12)
2011–2012PK-35 Vantaa (women)29(22)
2012–Åland United32(22)
National team
2002Nigeria women's national under-20 football team
2004–Nigeria women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 21 June 2014.
† Appearances (Goals).

Cynthia Uwak jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu July ni ọdun 1986. Arabinrin naa ṣere lọwọ fun Aland United ni Naisten Liiga, Finland[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Cynthia gba ami ẹyẹ gẹgẹbi Agbabọọlu lobinrin ilẹ Afirica ni ọdun 2006 ati 2007[4][5].
  • Cynthia kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2007 ati olympic ọdun 2008[6].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.eurosport.com/football/cynthia-uwak_prs333885/person.shtml
  2. https://fbref.com/en/players/5224f84d/Cynthia-Uwak
  3. https://allafrica.com/stories/201605110267.html
  4. https://goalballlive.com/african-women-footballer-of-the-year/
  5. https://www.allnigeriasoccer.com/read_news.php?nid=21748
  6. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/china2007/match-center/56318