Damon Wayans

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Damon Wayans
Orúkọ àbísọDamon Kyle Wayans
ÌbíOṣù Kẹ̀sán 4, 1960 (1960-09-04) (ọmọ ọdún 63)
New York City, U.S.
Medium
  • Stand-up
  • television
  • film
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Years active1981–present
GenresObservational comedy, black comedy, political satire
Subject(s)

Damon Kyle Wayans Sr. ( /ˈdmən ˈw.ənz/;[1] ojoibi September 4, 1960)[2] je alawada, osere, olukowe, ati atokun ara Amerika, ati ikan ninu awon Ẹbí Wayans. Wayans sise bi alawada ati osere ni gbogbo odun awon ewadun 1980, nigba to kopa ninu ere alawada Saturday Night Live.

Ninu ere alawada In Living Color gangan ni ebun re ti yo jade gege bi olukowe ati alawada lati 1990 di 1992. Lati igba na o ti kopa ninu filmu ati ere telifisan opolopo bii The Last Boy Scout ati Major Payne, ati ere telifisan My Wife and Kids. Lati 2016 de 2019, o sere gegebi Roger Murtaugh ninu ere telifisan Lethal Weapon.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. You nay it how? Archived May 27, 2010, at the Wayback Machine.
  2. "Damon Wayans Biography: Film Actor, Television Actor, Comedian, Director, Producer (1960–)". Biography.com (FYI / A&E Networks). Archived from the original on November 5, 2015. Retrieved September 6, 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)