Ìfòlókè 992 Dana Air

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Dana Air Flight 992)
Ìfòlókè 992 Dana Air
MD-83 flight deck
McDonnell Douglas MD-83, irú bàlúù tó jábọ́
Àkótán Ìjàmbá
Ọjọ́3 Oṣù Kẹfà 2012 (2012-06-03)
IrúÌwádìí únlọ lọ́wọ́
IbiÈkó, Nàìjíríà
06°34′38″N 003°19′16″E / 6.57722°N 3.32111°E / 6.57722; 3.32111Coordinates: 06°34′38″N 003°19′16″E / 6.57722°N 3.32111°E / 6.57722; 3.32111
Èrò146
Òṣìṣẹ́6
Injuriesunknown
Fatalities153 plus at least 10 on the ground
Survivors0
Aircraft typeMcDonnell Douglas MD-83
OperatorDana Air
Tail number5N-RAM
Flight originPápá Ọkọ̀ Òfurufú Káríayé Nnamdi Azikiwe, Abuja, Nigeria
DestinationPápá Ọkọ̀ Òfurufú Káríayé Múrítàlá Mùhammẹ̀d, Èkó, Nigeria

Ìfòlókè 992 Dana Air ni ifoloke oko akoero to fo lati Abuja lo si Èkó ni ojo 3 June 2012 to ja lu ile ise kapenta ati itewe ni adugbo Iju ni Èkó nitosi Pápá Ọkọ̀ Òfurufú Káríayé Múrítàlá Mùhammẹ̀d. Baalu na to je iru ti McDonnell Douglas MD-83 ti Dana Air nigbana unko ero 147 ati osise 6.[1][2]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Accident description". Aviation Safety Network. Retrieved 3 June 2012. 
  2. "Passenger plane crashes in Nigeria". CNN. Retrieved 3 June 2012.