Daniel Nathaniel
Ìrísí
Daniel Nathaniel | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 July 1992 | (ọmọ ọdún 32)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Men volleyball player |
Daniel Nathaniel(tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù keje ọdun 1992) jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin eléré ìdáyará volleyball tó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ sunshine apikers ti Akure ní orílẹ̀-èdè Nàíjíría.[1][2][3]
Igbèsi Aye Arakunrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Daniel kaweja pẹlú Electrical Electronic Engineering to ṣèrè gẹgẹbi setter fun Sunshine Spikers team ti volleyball ni Akure, ipinlẹ ondo[4][5].
Asèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Daniel jẹ captain fun awọn ọkunrin ti volleyball team ni ilẹ naigiria lapapọ[6]. Arakunrin naa yege ninu Volleyball league Division Akọkọ ni ilu Bauchi ni ọdun 2019[7][8][9].
Daniel siwaju awọn ọkunrin elere ti volleyball team ni ọdun 2019 lọsi game ilẹ afirica ni Morocco[10][11]. Arakunrin naa jẹ ara awọn team to yege ninu idije Regional Unity Cup ni ipinlẹ kwara ni ọdun 2022[12][13].
Àwọn Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ https://volleybox.net/daniel-nathaniel-p29364/indoor_tournaments
- ↑ https://www.brila.net/nigerias-mens-volleyball-team-set-for-aag-qualifier-in-abidjan/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ https://megasportsarena.com/nvbf-invite-30-players-ahead-of-2021-african-volleyball-championship/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-05. Retrieved 2023-03-05.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-02. Retrieved 2023-03-05.