Dar Mim (ilé ìsèwẹ́)
Ìrísí
Dar Mim (wọ́n da kalẹ̀ ní ọdún 2007) jẹ́ ilé ìsèwé kan ní fún àwọn ìwé ní èdè Arab ní Algiers, orílẹ̀ èdè Algeria. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé tí wọ́n ti ṣe ló gbajúmọ̀ káàkiri orílè-èdè.
Assia Ali Moussa ló dá Dar Mim kalẹ̀ ní ọdún 2007.[1] Yàtọ̀ sí àwọn ìwé, wọ́n tún ṣàgbéjáde ewì, ère, àti àwọn ìwádìí.[1] Àwọn ìwé Dar Mim kọ̀kan ti gba àmì-ẹ̀yẹ káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.[2]
Ọ̀pọ̀ àwọn iṣẹ́ wọn dá lórí àwọn ìwé tí àwọn òǹkọ̀wé ọmọ Algeria kọ ní èdè Arab, àwọn òǹkọ̀wé bi Djamila Morani, Ismail Yabrir, Malika Rafa, Samia Ben Dris, Saliha Laradji, Sofiane Mokhenache, àti Abdelouahab Aissaoui.[1]
Díẹ̀ nínú àwọn iṣẹ́ wọn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lā yatrak fī mutanāwal alatfāl ("Keep it Beyond the Reach of Children," novel) tí Sofiane Mokhenache (2012) kọ
- Mukhāḍ al-sulḥafā ("Tortoise Birth," novel) tí Sofiane Mokhenache (2016) kọ
- Tāj al-khaṭīʾa ("Crown's Sin") tí Djamila Morani (2017) kọ
- Al-duwāʾir wa al-ʾabwāb ("The Circles and Doors," novel) tí Abdelouahab Aissaou (2017) kọ
- Al-dīwān al-ʾasbartʾ ("The Spartan Court, novel) by Abdelouahab Aissaou (2017; winner of the 2020 Arabic Booker Prize (IPAF))[2]
- ānā wa ḥāyīm ("Me and Haim," novel) by Habib Sayah (longlisted for the IPAF in 2019)[3][4]
- ʿAin ḥamūrābi ("The Eye of Hammurabi," novel) ti Abdulatif Ould Abdullah (2020; shortlisted for the 2021 IPAF) kọ.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Bentoumi, K. (2020). Power and publishing : Contemporary arabophone and francophone Algerian literature and its national and transnational conditions of production (Order No. 28485424). Available from ProQuest Dissertations & Theses Global. (2508835883).
- ↑ 2.0 2.1 "The Spartan Court | International Prize for Arabic Fiction". www.arabicfiction.org. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ "Me and Haim | International Prize for Arabic Fiction". www.arabicfiction.org. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ Ghanem, Nadia (2019-01-22). "‘Me and Haim’: an Algerian Odyssey Through Racism". ARABLIT & ARABLIT QUARTERLY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-25.
- ↑ "The Eye of Hammurabi | International Prize for Arabic Fiction". www.arabicfiction.org. Retrieved 2022-03-25.