David Crosby
Ìrísí

David Crosby
ẹ̀yà | akọ ![]() |
---|---|
country of citizenship | Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà ![]() |
name in native language | David Crosby ![]() |
orúkọ àbísọ | David Van Cortlandt Crosby ![]() |
orúkọ àfúnni | David ![]() |
orúkọ ìdílé | Van Cortlandt, Crosby ![]() |
ọjó ìbí | 14 Oṣù Ògún 1941 ![]() |
ìlú ìbí | Los Angeles ![]() |
ọjó ikú | 18 Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ 2023 ![]() |
ibi ikú | Santa Ynez ![]() |
òùnfà ikú | Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 ![]() |
bàbá | Floyd Crosby ![]() |
ìyá | Aliph Van Cortlandt Whitehead ![]() |
ègbón àti àbúrò | Ethan Crosby ![]() |
ọmọ | James Raymond, Beckett Cypher ![]() |
Ebí | Van Cortlandt family, Van Rensselaer family ![]() |
native language | gẹ̀ẹ́sì ![]() |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì ![]() |
writing language | gẹ̀ẹ́sì ![]() |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Cate School, Santa Barbara City College ![]() |
work period (start) | 1964 ![]() |
work period (end) | 2023 ![]() |
medical condition | type 2 diabetes ![]() |
discography | David Crosby discography ![]() |
genre | rock music, folk rock, country rock, jazz fusion ![]() |
record label | Atlantic Records, A&M Records, Rhino ![]() |
award received | MusiCares Person of the Year, Rock and Roll Hall of Fame ![]() |
official website | https://davidcrosby.com/ ![]() |
copyright representative | SESAC ![]() |
copyright status as a creator | works protected by copyrights ![]() |
facial hair | walrus moustache ![]() |
David Van Cortlandt Crosby (tí wón bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ, ọdún 1914, tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún, ọdún 2023)[1]jẹ́ akọrin àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ohun tí ó kọ́kọ́ sọ ọ́ di gbajúmọ̀ ni jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹ "the Byrds." Crosby ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn àwo-orin adáṣe mẹ́jọ, bótilẹ̀jẹ́pé lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan ni, lákòókò iṣẹ́ rẹ̀. Àwọ rẹ̀ kan tí ó ṣìfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1197 ni àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Tí MO Bá Le Rántí Orúkọ Mi Nìkan (If I Could Only Remember My Name)."[2]
Àwọn itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "David Crosby, Folk-Rock Voice of the 1960s, Dies at 81". The New York Times. 2023-01-20. Retrieved 2023-04-18.
- ↑ Ankeny, Jason (1941-08-14). "David Crosby Biography, Songs, & Albums". AllMusic. Retrieved 2023-04-18.