Jump to content

David Wilson (agbábọ́ọ̀lù)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
David Wilson
Personal information
Ọjọ́ ìbí17 December 1908[1]
Ibi ọjọ́ibíHebburn, England[2]
Ọjọ́ aláìsí22 February 1992(1992-02-22) (ọmọ ọdún 83)
Ibi ọjọ́aláìsíGlasgow, Scotland[1]
Ìga5ft 9in[3]
Playing positionCentre forward
Youth career
Hebburn Colliery[4]
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1928–1945Hamilton Academical329(245)
Stranraer 
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

David Wilson (tí wọ́n bí ní 17 December 1908, tó sì ṣaláìsï ní 22 February 1992)[2] jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, tó gbá bọ́ọ̀lù fún Hamilton Academical F.C. àti Stranraer F.C. gẹ́gẹ́ bí i ọkàn lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà.[3]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tó máa ń góòlù jù.[5][6] Ó gbá góòlù 246 ní sáà mọ́kànlá kí ogún àgbáyé kejì tó wáyé. [7] Wọ́n sì yàn án gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù tó mọ̀ ọ́n gbá jù.[8][9]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Statutory registers - Deaths - Search results[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], ScotlandsPeople
  2. 2.0 2.1 Emms, Steve; Wells, Richard (2007). Scottish League Players' Records 1890/91 to 1938/39. Nottingham: Tony Brown. ISBN 978-1-899468-66-9. 
  3. 3.0 3.1 Wilson, David (1928) Archived 2022-10-23 at the Wayback Machine., Hamilton Academical Memory Bank
  4. John Litster (October 2012). A Record of pre-war Scottish League Players. Scottish Football Historian magazine. 
  5. Scotland - List of Topscorers, RSSSF, 20 June 2019
  6. "Soccerbase". Archived from the original on 4 September 2009. Retrieved 12 March 2008.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Club History". Hamilton Academical F.C. Archived from the original on 17 January 2010. Retrieved 15 February 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named scotlge35
  9. 75 years since Accies' Scottish Cup final against Rangers, Daily Record, 15 April 2010