Jump to content

Democratic Green Party of Rwanda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Democratic Green Party of Rwanda
French nameParti vert démocratique du Rwanda
Kinyarwanda nameIshyaka Riharanira Demokarasi no Kurengera Ibidukikije
ÀrẹFrank Habineza
Ìdásílẹ̀14 Oṣù Kẹjọ 2009 (2009-08-14)
Ọmọ-ẹgbẹ́500,000 (claimed)[1]
Ọ̀rọ̀àbáGreen politics
Green liberalism
Liberal democracy
Ipò olóṣèlúCentre to centre-left
Ìbáṣepọ̀ akáríayéGlobal Greens
Chamber of DeputiesÀdàkọ:Composition bar
Ibiìtakùn
rwandagreendemocrats.org

Ẹgbẹ́ òsèlú Democratic Green Party of Rwanda (DGPR; Faransé: Parti vert démocratique du Rwanda, PVDR; Àdàkọ:Lang-rw, IRDKI) jẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú kan ní Rwanda, tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 2009. Wọ́n ṣe ìforúkọsílẹ̀ ẹgbẹ́ náà ní oṣù kẹjọ ọdún 2013, nítorí pé ó pé kí wọ́n tó fi orúkọ ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 2013, wọn kò padà ní àǹfààní láti kópa nínú ìdìbò sílé ìgbìmọ̀ aṣofin Rwanda ti ọdún 2013. Ète ẹgbẹ́ òsèlú náà ni láti lo àwọn ọ̀nà tí kò mú wàhálà dání, jà fún dídín owó àwọn ǹkan ọ̀gbìn àti oúnjẹ kù. Wọ́n gbàgbọ́ pé ara ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn ni "ẹ̀tọ́ sí ẹ̀mí, òmìnira, ìpàdé àlàáfíà, láti sọ tinú wọn jáde, láti sìn Ọlọ́run wọn àti láti ṣe ǹkan tí ó ń fún wọn ní ìdùnnú", àti pé Ọlọ́run ni ó ń fún yàn ní àwọn ànfàní yìí.[2]

Wọ́n dá ẹgbẹ́ òsèlú náà kalẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ ọdún 2009, wọ́n sì ní ète láti kópa nínúÌdìbọ̀ ààrẹ ọdún 2010. Ṣùgbọ́n wọn kò ríbi fi orúkọ ẹgbẹ́ wọn sílè.[3]

Wọ́n padà fi orúkọ ẹgbẹ́ òṣèlú náà sílè ní oṣù kẹjọ ọdún 2013, ṣùgbọ́n wọn kò ríbi kópa nínú Ìdìbò sípò ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ti ọdún 2013.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Rwanda's only registered opposition party picks candidate to face Kagame". Africa News. 
  2. "National Political Platform". Democratic Green Party of Rwanda. Archived from the original on 23 June 2018. Retrieved 23 June 2018. 
  3. Wadhams, Nick (2010-05-05). "Rwanda: Anti-Genocide Law Clashes with Free Speech". Time. Archived from the original on 2010-05-09. https://web.archive.org/web/20100509201508/http://www.time.com/time/world/article/0,8599,1986699,00.html. Retrieved 5 May 2010. 
  4. Tom Lansford (2015) Political Handbook of the World 2015, CQ Press