Denise Mobolaji Ayaji-Williams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Denise Mobalaji Ajayi-Williams
Orílẹ̀-èdèNigerian, American
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of California, Riverside, Golden Gate University
Iṣẹ́Novelist, Author, Animator, Short-story writer, Journalist, Social Entrepreneur
OrganizationWorking Mom in 1920s; WM Journal Magazine; Silicon Valley-Nigerian Economic Development; Bolaji Animations Production & Publishing Studios (BAPS)
Gbajúmọ̀ fúnWriting Children Comics, Journalism, Philanthropy and Women Freedom
Notable workAkiti The Hunter (2015) Part I, “Akiti The Hunter” (2016) Part II
Parent(s)Chief Temitope Ajayi (aka 'Mama Diaspora')
Websiteakitithehunter.com

Denise Mobalaji Ajayi-Williams ni aṣàkóso àti olùdásílẹ̀ Silicon Valley- Nigerian Economic Development Inc. (SV-NED).[1][2] SV-NED Inc jẹ́ ìtàkùn tó so Silicon Valley àti gbogbo ayé pọ̀. Ní ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn, SV-NED Inc. ti ní tó ènìyàn 1 billion, tí wọ́n sì ti ní ìbáṣepọ̀ tó dánmọ́rán pẹ̀lú àwọn oníṣòwò tóju ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta lọ (50 thousand). Williams ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alákòóso fún ilé-iṣẹ́ márùn-ún, tí ń ṣe SV-NED Inc., Global Connection for Women Foundation, Sky Clinic Connect, Numly, àti Collabful.[3][4][5][6][7]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Williams gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ Economics láti University of California, ní Riverside, àti oyè Masters nínú ìmọ̀ Business Administration pẹ̀lú Marketing, láti Golden Gate University, Ageno School of Business.[8] Williams ṣiṣé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ètò-ìlera, bí i Kaiser Permanente, Gilead Sciences, Abbott Laboratories, àti State of CA Department of Public Health. Williams ti gba oríṣiríṣi àmì-ẹ̀yẹ bí i US Congressional Award fún ìdásí tó tayọ jù lọ láti ọwọ́ Outstanding Contributions Congresswoman Barbara Lee, èyí tó jẹ́ àmì-ẹ̀yẹ ti US Senatorial láti Senator Dianne Feinstein fún adarí tó tayọ jù lọ, àti àmi-ẹ̀yẹ Visionary láti ọwọ́ Actor Danny Glover.[9]

Iṣé tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ti ṣàfihàn Williams ní oríṣiríṣi ìwé-ìròyìn bí i Forbes,[10] CNBC, GritDaly,[11] Huffington Post,[12] Guardian, Thrive Global, àti Black Enterprise. Ohun tó jẹ Williams lógún jù lọ ni láti pèsè ìtàkùn tó máa so ìmọ̀-ẹ̀rọ Silicon Valley pọ̀ mọ́ gbogbo àgbáyé. Tí kò bá ṣiṣé, ó máa ń dásí ìmọ̀-mọ̀-ọ́n-kọ mọ̀-ọ́n-kà àwọn ọmọdé, èyí tó sì hàn gbngba nínú àwọn ìwé rẹ̀ fún àwọn ọmọdé. Akiti the Hunter, jẹ́ ìwé ilẹ̀ Afirika àkọ́kọ́ tó máa dá lórí akitiyan àti àwọn àkàndá ènìyàn. Wọ́n gbìyànjú láti ṣe ìwé Akiti the Hunter sínú fọ́nrán, tí ó máa ṣe é wò.[13][14][15]

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ajayi-Williams ní ọmọkùnrin kan pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Hayden Williams III, tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ WM Journal àti Working Moms in 1920s organisation.[16][17]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "West Africa finds an unlikely home in Silicon Valley". Grit Daily News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-21. Retrieved 2021-04-23. 
  2. Hassan, Binta (2016-02-04). "6 Nigerians Making A Difference". PR2J3C4 - Nigeria @ Her Best (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-05-09. Retrieved 2021-04-23. 
  3. Mary (2015-09-04). "'Akiti the Hunter' brings a Black hero to children's literature". San Francisco Bay View (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  4. "Author Denise Ajayi-Williams Kicks off Book Tour of "Akiti the Hunter," African Super Hero | Post News Group". Archived from the original on June 7, 2020. Retrieved June 7, 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Black History Month Storytime with author Bolaji Ajayi". Mill Valley, CA Patch (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-02-20. Retrieved 2021-04-23. 
  6. Ajayi-Ore, Lilian (2016-03-02). "An Iconic Woman on the RISE, Denise Mobolaji Ajayi-Williams". HuffPost (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  7. "Bold TV". Bold TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  8. "Google Translate". July 25, 2019. 
  9. "The Nation". Issuu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). October 9, 2011. Retrieved 2021-04-23. 
  10. "Denise (Ajayi) Williams". Forbes Councils (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  11. "West Africa finds an unlikely home in Silicon Valley". Grit Daily News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-21. Retrieved 2021-04-23. 
  12. Ajayi-Ore, Lilian (2016-03-02). "An Iconic Woman on the RISE, Denise Mobolaji Ajayi-Williams". HuffPost (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  13. "EVENTS GALLERY — SV-NED". www.svned.com. Archived from the original on 2019-04-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. Hamed, Idowu. "Ooni of Ife, Makes His Grand Entrance to Silicon Valley". Startrend International Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  15. Williams III, Hayden (2017-11-30). "'His Imperial Majesty Has Arrived' — Nigerian King Visits Silicon Valley". Bold TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-23. 
  16. Hazelwood, Janell (December 9, 2015). "From the Mouths of Babes: How a Mother, Inspired by Her Son, Is Diversifying World of Superheroes". Black Enterprise. https://www.blackenterprise.com/akiti-the-hunter-denise-ajayi-williams-publishing-tips-african-superhero/. 
  17. "Posts by Hayden Williams III". Bold-Bold TV. Archived from the original on April 5, 2016. https://web.archive.org/web/20160405232039/http://bold.global/author/haydenw3/.