Jump to content

Diesel Locomotive Factory, Marhowrah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

The Diesel Locomotive Factory, Marhowrah jẹ́ àpapọ̀ ilé iṣẹ́ ọkọ̀ ojú-irin ti GE ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà pẹ̀lú àwọn reluwé ti orílẹ̀-èdè India fún ṣíṣe ọkọ̀ ojú irin tí ìwọ̀n agbára gíga rẹ̀ tó 1000 tí wọ́n rọ fún bíi ọdún mẹ́wàá síwájú si láti ṣiṣẹ́ lórí àwọn òpópónà ojú-irin orílẹ̀-èdè India.[1] Ilé iṣẹ́ yìí wà ní Marhaura (tí wọ́n sì tún máa ń kọ ọ́ báyìí Marhowrah) tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe ọkọ̀ náà ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2018.[2]

Ilé iṣẹ́ náà sì tún ṣe ibi ìtúnkọ̀ ṣe méjì ni ìlú Gandhidham ní Gujarat àti Roza ní Uttar Pradesh.[3]

  1. "Diesel Locomotive Factory at Marhowra, Bihar". www.kportal.indianrailways.gov.in. Archived from the original on 2023-05-15. Retrieved 2023-05-15. 
  2. "Explained: How a GE factory at Marhowra became a Make in India flagship". Business Standard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-26. 
  3. "Infrastructure Boost! Indian Railways Set To Get Modern ‘Make In India’ Locomotives; Check Out Images And Facts". vote.us.org. 2017-06-19. Archived from the original on 2017-12-14. Retrieved 2017-12-14.