Jump to content

Dilma Rousseff

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Dilma Vana Rousseff)

Dilma Rousseff
Official portrait of Dilma Rousseff
36th President of Brazil
In office
1 January 2011 – 31 August 2016
Suspended: 12 May 2016 – 31 August 2016
Vice PresidentMichel Temer
AsíwájúLuiz Inácio Lula da Silva
Arọ́pòMichel Temer
Chief of Staff of the Presidency
In office
21 June 2005 – 31 March 2010
ÀàrẹLuiz Inácio Lula da Silva
AsíwájúJosé Dirceu
Arọ́pòErenice Guerra
Minister of Mines and Energy
In office
1 January 2003 – 21 June 2005
ÀàrẹLuiz Inácio Lula da Silva
AsíwájúFrancisco Luiz Sibut Gomide
Arọ́pòSilas Rondeau
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Dilma Vana Rousseff

14 Oṣù Kejìlá 1947 (1947-12-14) (ọmọ ọdún 76)
Belo Horizonte, Brazil
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Labour Party (1979–1986)
Workers' Party (1986–present)
(Àwọn) olólùfẹ́Cláudio Galeno Linhares (1967–1969)
Carlos Paixão de Araújo (1969–2000)
Àwọn ọmọ1
Alma materFederal University of Minas Gerais
Federal University of Rio Grande do Sul
University of Campinas
Signature
WebsiteOfficial website

Dilma Vana Rousseff (Pọrtugí Brasi: [ˈdʒiwmɐ χuˈsɛf], ojoibi December 14, 1947) je oloselu ati Aare orile-ede Brasil tele, lati 1 January 2011 de 31 August 2016. Ohun ni obinrin akoko ti yio bo si ipo yi. Rousseff je onimo oro-okowo. Ni 2005, ohun ni obinrin akoko to di Oga Agba awon Osise Brasil, nigbati Aare Luiz Inácio Lula da Silva yan sipo na.[1]



  1. Bennett, Allen."Dilma Rousseff biography" Archived 2010-04-09 at the Wayback Machine.. Agência Brasil. August 9, 2010.