Luiz Inácio Lula da Silva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Luiz Inácio Lula da Silva
Portrait of Luiz Inácio Lula da Silva
35th President of Brazil
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2023
Vice PresidentGeraldo Alckmin
AsíwájúJair Bolsonaro
In office
1 January 2003 – 1 January 2011
Vice PresidentJosé Alencar
AsíwájúFernando Henrique Cardoso
Arọ́pòDilma Rousseff
Leader of the Workers' Party
In office
10 February 1980 – 15 November 1994
AsíwájúPosition established
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹ̀wá 1945 (1945-10-27) (ọmọ ọdún 78)
Caetés, Brazil
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPartido dos Trabalhadores (PT)
(Àwọn) olólùfẹ́Maria de Lurdes (1969-1971; Deceased)
Marisa Letícia Rocco Casa (1974-2017)
Rosângela Lula da Silva (2022-)
Àwọn ọmọFábio Luís
Lurian Cordeiro
Luís Cláudio
Marcos Cláudio (Adopted)
Sandro Luís
ResidenceSão Bernardo do Campo
ProfessionAutomotive worker
Union organizer
SignatureLula (Signature of Luiz Inácio Lula da Silva)

Luiz Inácio Lula da Silva (Pípè ni Potogí: [luˈis iˈnäsjʊ ˈlulɐ dä ˈsiʊ̯vɐ]; ojoibi 27 October 1945), o gbajumo gege bi Lula,[2] ni Aare orile-ede Brazil lati 2003 titi 2011. A tún yàn sípò ààrẹ fún sáà kẹta ni odun 2022, tí à sì ṣe ìbúra-wọlé fun ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 2023. Oun ni Ààrẹ orílè-èdè Brazil lọ́wọ́ lọ́wọ́.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Folha Online – Mundo – "Lula é um católico a seu modo", diz d. Cláudio Hummes – 06/04/2005". .folha.uol.com.br. 1970-01-01. Retrieved 2010-10-03. 
  2. Luiz Inácio da Silva was Lula's full birth name, which he used from 1945 to 1982, but he has been known as Lula since childhood; the nickname itself is a hypocoristic for Luiz with consonantal reduplication. Consequently, Lula became the name by which he was known throughout his career as a metallurgical worker, and as he emerged in the national scene as a union leader, and for all his political life. In 1982, in order to run for governorship of the state of São Paulo, Lula changed his legal name, adding the nickname Lula by which he was nationally known. Under Brazilian electoral laws at the time, one could only use one's legal name to run for public office. Currently, Brazilian newspapers refer to him either (more formally) using his full name Luiz Inácio Lula da Silva or (informally or on second reference) only his moniker Lula.