Jump to content

Dj snake

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
DJ Snake
DJ Snake in 2020
DJ Snake in 2020
Background information
Orúkọ àbísọWilliam Sami Étienne Grigahcine
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹfà 1986 (1986-06-13) (ọmọ ọdún 38)
Parisi, Faransé
Ìbẹ̀rẹ̀Ermont, Faransé
Irú orin
Occupation(s)
 • Atọ́kùn rẹkọ̀dù
 • DJ
 • Akọrin
Years active2009– Di àsìkò yìí
Labels
Associated acts
Websitedjsnake.com

William Sami Étienne Grigahcine ( wọ́n bi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún, ọdún 1986), tí wọ́n mọ orúkọ-ìtàgé rẹ̀ ní DJ Snake, jẹ́ Atọ́kùn rẹ́kọ̀dù Faransé. Ó àkọ́kọ́ rí ìfojúsí lára láàgbáyé ní ọdún 2013 láti ara wí pé ó ṣe ohun-èlò ajẹmórìn tí ó ní ṣe pẹ̀lú àgbègbè rẹ̀ tó dá ní tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Turn Down for What" (featuring Lil Jon).[1][2][3][4][5]

Ó ṣe àkọ́kọ́ orin àgbáyé pẹ̀lú àwọn orin tó dá kọ "Bird Machine" and "Turn Down for What" ni ọdún 2013.[1][6][7] "Bird Machine" ṣe ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú Akẹgbẹ́ olórin Faransé Alesia. Orin àdákọ náà jẹ́ gbígbà lọ́wọ́ Mad Decent, rẹ́kọ̀dù lébẹ́lì tí ó wà ní Los Angeles olówó rẹ̀ jẹ́ Diplo.

Wọ́n kéde DJ Snake láti má ṣíṣe lórí ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú Diplo, tí wọ́n fẹ́ gbé orin náà jáde ọdún 2014; orin náà padà jáde mí ọdún 2015 released in 2015 as the single "Lean On" tó ṣe ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú àti Diplo's Major Lazer.[8][9][10] Ní ọjọ́ kọgbọ̀n oṣù kẹ́rin ọdún 2014, DJ Snake bọ́ sí ipò "Òṣèré tó gba wíwò" láti ọwọ́ FoxWeekly.[11] Òun àti Dillon Francis gba ìkéde gẹ́gẹ́ bí àwọn Òṣèré méjì tí wọ́n jẹ́ igi lọ́gbà ẹ̀yìn fún ara wọn fún sọ́mà Mothership Tour ni ọdún 2014 pẹ̀lú Skrillex.[12] Ní oṣù kẹ́ta ọdún 2018, Billboard Sọ orúkọ DJ Snake ní Òṣèré kẹsàn-án ní òdìnwọ̀ ọdún 2018 fún àwọn Akọrin-óníjó tí wọ́n pẹ̀ ní Billboard Dance 100.[13][14]

 1. 1.0 1.1 "Dj Snake". TomorrowWorld.com. Archived from the original on 2 January 2014. Retrieved 31 December 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 2. "DJ Snake & Nostradamus – Pop That Pissy". EDMTunes.com. 9 October 2013. Retrieved 31 December 2013. 
 3. "DJ Snake – 'I want to make the world dance!'". In The Red. Archived from the original on 9 October 2013. Retrieved 31 December 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 4. "DJ Snake – The Year of the Snake". Life and Times. 18 November 2013. Retrieved 31 December 2013. 
 5. "On the right track, baby". Time Out. Archived from the original on 3 January 2014. Retrieved 31 December 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 6. "DJ SNAKE ANNOUNCES AUSTRALIAN TOUR DATES". Stoney Roads. Retrieved 31 December 2013. 
 7. "Imperial ft DJ Snake & Motez". Eventfinder.co.nz. Archived from the original on 14 October 2014. Retrieved 31 December 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 8. "Dillon Francis & DJ Snake Preview New Track At TomorrowWorld". YourEDM.com. 10 October 2013. Archived from the original on 7 November 2017. Retrieved 31 December 2013. 
 9. "Watch DJ Snake Drop a New Collaboration with Diplo in Chicago". Do Androids Dance?. Retrieved 31 December 2013. 
 10. Beauchemin, Molly (2 March 2015). "Diplo's Major Lazer Share New Track "Lean On," Featuring MØ and DJ Snake". Pitchfork.com. Pitchfork Media. Retrieved 25 June 2015. 
 11. "#8. DJ Snake [artist to watch.]". Fox Weekly. Archived from the original on 2 May 2014. Retrieved 30 April 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 12. Kevin Rutherford (10 March 2014). "Skrillex Announces Mothership Tour 2014, New Album (Updated)". Billboard. Retrieved 20 July 2014. 
 13. "Billboard Dance 100 Artists of 2018: The Complete List". Billboard. https://www.billboard.com/articles/news/dance/8257429/billboard-dance-100-2018. Retrieved 23 March 2018. 
 14. "The Chainsmokers named top DJs in the world by Billboard". WJBD Radio. Archived from the original on 22 March 2018. Retrieved 23 March 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)