Dogville

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dogville jẹ fiimu 2003 [1] ti Lars von Trier ko ti ode tun daari, peelu awon osere bi Nicole Kidman, Lauren Bacall, Paul Bettany, Chloë Sevigny, Stellan Skarsgård, Udo Kier, Ben Gazzara, Patricia Clarkson, Harriet Andersson, ati James Caan pẹlu John Hurt ti n se aroye. O je owe ti o ipele kekere - bi iseto lati so itan ti Grace Mulligan (Kidman), obinrin kan to n farapamon fun mobsters, ti o de si ilu kekere to wa ni ori oke Dogville, Colorado, peelu ipese àbo ni ipaaro fun ise asekara.

Fiimu naa wa ni idije fun Palme d'Or ni odun 2003 Cannes Film Festival.[2] O ṣe afihan ni ọpọlọpọ awọn ayẹyẹ fiimu ṣaaju gbigba afihan oni gbede ni ilu America ni Oṣu Kẹta Ọjọ kerin dinlogbon, Ọdun 2004.

Ahun Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itan ti Dogville ni a sọ ni awọn ori mẹsan ati asọtẹlẹ kan, pẹlu apejuwe gbolohun kan ti ipin kọọkan ti a fun ni fiimu naa.

Awon Osere[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

1. John Hurt bi Alaroye
2. Nicole Kidman bi Grace Margaret Mulligan
3. Lauren Bacall bi Ma Ginger
4. Paul Bettany bi Tom Edison. Jr
5. Chloe Sevigny bi Liz Henson
6. Stellan Skarsgard bi Chuck
7. Jean- Marc Barr ni Arakunrin to ni fila nla
8. Ben Gazzara bi Jack Mckay
9. Patricia Clarkson bi Vera
10. Shauna Shim bi June
11. Bill Raymond bi Mr. Henson

Dogville: Won yaa ere na ni ọdun 2001 ni ipele iṣaaju-iṣelọpọ lati ṣe idanwo boya imọran ti iwoye ṣoki yoo ṣiṣẹ. Fiimu iseju meedogun ti ṣe affihan awọn oṣere Danish Sidse Babett Knudsen (bi Grace) and Nikolaj Lie Kaas (bi Tom). Ni ipari inu Lars von Trier dun pẹlu awọn abajade gbogbogbo. Bayi, irare ati awọn olupilẹṣẹ pinnu lati lọ siwaju pẹlu iṣelọpọ ti fiimu na. A ko fi idanwo naa han ni gbangba, ṣugbọn o ṣe ifihan lori disiki keji ti DVD Dogville (2003), ti a se afihan re ni Oṣu kọkanla ọdun 2003. [3]

Fiimu naa se akowole milionu kan peelu egberun lona edegbeta dola ni ọja AMẸRIKA ati milionu meedogun peelu egberun lona ogofa ole maraun dola lati iyoku agbaye fun apapọ milionu merin dinlogun peelu egberun lona egbeta milionu dola. A ṣe ifilọlẹ fiimu naa ni awọn ile iṣere mẹsan nikan.[4] Ni ile Denmark, fiimu naa gba milionu kan peelu peelu egberun lona igba dola. Orilẹ-ede ti fiimu na ti pawo ju ni ile Itila pelu milionu meta pelu egberun lona igba dola[5]

• 1st - Mark Kermode, BBC Radio Marun Live
• 2nd - J. Hoberman, Village Voice
• 3rd - ìwò, Village Voice
• 4th - Dennis Lim, Village Voice
• 5th - Jack Mathews, New York Daily News
• 8th - JR Jones, Chicago Reader
• n / a - David Sterritt, The Christian Science Monitor
• n / a - Ron Stringer, LA osẹ-

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

1. "Lars Von Trier's Deconstructive, Avant Garde Cinema". https://theplaylist.net/lars-von-trier-deconstructive-20160728/.
2. "Festival de Cannes: Dogville". festival-cannes.com. Retrieved 2009-11-05.
3. "Dogville (2003)". British Film Institute. Archived from the original on 20 August 2012. Retrieved 7 July 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
4. "Dogville (2004)". Box Office Mojo. Retrieved 2010-02-25.
5. "Dogville".
1. "Lars Von Trier's Deconstructive, Avant Garde Cinema". https://theplaylist.net/lars-von-trier-deconstructive-20160728/.
2. "Festival de Cannes: Dogville". festival-cannes.com. Retrieved 2009-11-05.
3. Dogville: The Pilot on IMDb
4. "Dogville (2004)". Box Office Mojo. Retrieved 2010-02-25.
5. Empty citation (help)