Don Moen
Don Moen | |
---|---|
Moen in 2009 Moen in 2009 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Donald James Moen |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹfà 1950 |
Irú orin | |
Occupation(s) | Musician |
Instruments |
|
Years active | 1984–present |
Labels |
|
Website | donmoen.com |
Donald James Moen (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹfà, ọdún 1950) jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè America, atẹ-dùrù, òǹkọ-orin tó sojú dé àwọn orin ti ẹ̀mí.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Moen dàgbà sí Two Harbors, ní Minnesota, níbi tí ó ti kàwé girama, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ọdún 1968.[1] Moen lọ sí Oral Roberts University, èyí tó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí àwọn Kìrísìtẹ́ẹ́nì.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó di olórin nínú ẹgbẹ́ Living Sound fún iṣẹ́ ìránṣẹ́ Terry Law Ministries, ó sì rin ìrìn-àjò pẹ̀lú Terry Law fún ọdún mẹ́wàá.[2] Lẹ́yìn èyí, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Integrity Media fún ogún ọdún, gẹ́gẹ́ bí i olùdarí àti Ààrẹ Integrity Music, Ààrẹ Integrity Label Group, àti aṣagbátẹrù àwọn àwo-orin Integrity Music.[3] Ó kúrò ní Integrity Media ní oṣù kejìlá ọdún 2007, láti ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ tirẹ̀, tó pè ní The Don Moen Company.[4] The Don Moen Company ra MediaComplete, èyí tó jẹ́ ti ilé-ìjọsìn kan tó ṣẹ̀dá MediaShout. Moen di olóòtú ètò Don Moen & Friends ní ọdún 2009. Moen gba Dove Award fún iṣẹ́ ribiribi rẹ̀ nínú orin God with Us, lẹ́yìn tí wọ́n yan àwọn orin rẹ̀ fún ìgba àmì-ẹ̀yẹ.
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Moen àti ìyàwó rẹ̀ Laura, ti fẹ́ran wọn láti ọjọ́ kọkandínlógún oṣù Karùn-ún ọdún 1973. Wọ́n jìjọ bí àwọn ọmọ márùn-ún.[5][6]
Àtòjọ orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Give thanks (1986)
- Steadfast Love (1988)
- Bless the Lord (1989)
- Christmas (1990)
- Eternal god (1990)
- Worship With Don Moen (1992)
- God With Us (1993)
- Trust in the Lord - Live Worship with Don Moen (1994)
- Mighty Cross (1994)
- Rivers of Joy (1995)
- Emmanuel has Come (1996)
- Praise with Don Moen (1996)
- Let Your Glory Fall (1997)
- Good for Us (1998)
- God is Good - Worship with Don Moen (1998)
- En Tu Presencia (1999)
- More of You, Lord - Praise with Don Moen Volum 2 (1999)
- Give Thanks (1999)
- The Mercy Seat (2000)
- Heal Our Land (2000)
- I Will Sing (2000)
- God Will Make a Way (2003)
- God in Us (2001)
- Trono de Gracia (2003)
- Thank You Lord (2004)
- 23 Nonstop Best Songs (2005)
- Arise: The Worship Legacy of Don Moen (2006)
- Hiding Place (2006)
- With a Thankful Heart: The Best of Don Moen (2011)
- Uncharted Territory (2011)
- Hymnbook (2012)
- Christmas A Christmas of Hope (2012)
- Ultimate Collection (2013)
- Hymns of Hope (2013)
- By Special Request: Volume One (2015)
- God Will Make a Way: A Worship Musical (2016)
- Grace (Don Moen & Frank Edwards) (2016)
- By Special Request: Volume Two (2017)
- Jehovah Wezi Manga (Don Moen & the Mahotella Queens) (2017)
- Don Moen Collection (2020)
- A Hungry Heart (2020)
- Return to Me (2021)
- Great is Your Mercy (2022)
- Goodness of God (feat. Rachel Robinson) (2022)
- Upper Room Sessions (2022)
- Worship Today with Don Moen (2023)
- By Special Request: Vol. 3 (2023)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ auntyfaith (July 17, 2019). "The Biography of Don Moen". Auntyfaith.com. Archived from the original on February 26, 2021. Retrieved May 4, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ [1] Archived January 16, 2010, at the Wayback Machine.
- ↑ Swartzendruber, Jay (February 2007). "Industrybeat: Moen of Many Hats". CCM Magazine 29 (8): 22. ISSN 1524-7848.
- ↑ "Moen's Move: Don Moen to leave Integrity Media to form new companies". Crossrhythms.co.uk. August 1, 2008. Archived from the original on October 15, 2013. Retrieved August 22, 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Sseruyigo, Aaron (2022-05-20). "'Eternally grateful': Don Moen celebrates 49 years in marriage". Breaking news on Christianity in Uganda and World (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-03-07.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:02